Você está na página 1de 1

OFO OB Yoruba

Aja ni ngba ni leba ntele ntele Esinsin ko ku ate ileke Royin royin lojo iregun kowaju Eji a pada sehin A da foba Leyo Ajori Oba ajeine tan ogbera Oba ajere yokun leyo Eke pa obi, obi di Odale pa obi, obi si sigo sigo Oninure pa obi, obi yan gberegede A da fun Ojodu, Omo Aro ni ife Ojodu ni baba je Baba mu lobun nitolo O ni, obi ti o hun pa yi, yio yan A si yan gberegede.