Você está na página 1de 3

Oríkì Èṣù

Èṣù láàlú

Arẹẹyinjú légun lọ

Bákeré ọọ dádá

Ègbè lẹẹyìn ẹlẹẹbọ

Ènìní lẹẹyìn ẹni ó kọọ rọọ Òdùmàrè

Bákeré ò lórúnkún ẹjọẹ

Èṣù ỌỌ̀ dàrà ò lórí a gbẹẹrù lé

Àfi ṣóńṣó abẹ

Èṣù Bèlèké òkú Ìgbọẹnná

Bákeré olówó ẹyọ

Èṣù tí í ṣowó

Èṣù tí í ṣọmọ

Àyígbìn

Ọba Ẹbọra nílé Kétu

Asánnà

Ayẹọ nà

Ògìrìgìrì n tọẹnà ṣe

Òrìṣà tí í pọnmọ rèlú ìlájé

Òrìṣà tí í pọnmọ rèlú ìlọẹrọọ

Èṣù ní í kóre wálé

Ẹlẹẹgbára ní í gbẹẹbọ ròkun

Ẹlẹẹgbára ní í gbẹẹbọ rọọ sà

Ẹlẹẹgbára ní í kó gbogbo ibi ròkun rọọ sà

Oníbodè tí dènà ibi


Adurá Esu

"Exu Oni bodê Orum

Oxeturá eni omo iá eni o mo babá

Ti Adi toju bi omo Elegbara iuô la pe loni uá loni i bi omo ti njé

Iá re uara nitori rogbô diã ilê aiê po jojô ogum ni uá

Ogum lehim ilê aiê ogum ojô jumo ogum

Ati iê to mu olomo ki o ma mo omo re to mu ore di otá arauom

To mu eni du ipo omo lakeji to jeki a fé oju mo nkã eni

Auá bebê fum abó re Exu Lalu uá gbô orô ati laroiê

Uá so uá babá njadê lo so uá ti a pá padá uá le uá ki ogum

Aiê ma le riuá gbe se Exu olo na onã ti Exu ba si enikã ki di uá si onã fun

Uá eniti Exu ba si onarê lo segum aiê se uani olussegum ki otá

Ma leri na gbe se eni onã re ba si pereguedê loni alafia babá orô Exu Odara da abó re bouá loni

Axé axé axé."

.......................................................................................
"Igbá Exu Lalu

Exu ogá onilu

Atobajaiê, elessó ogum

Orili logum

Alagadá eié

Orokô ni ojô ebô lè

Exu tabirigbongbom

Abonijauá kumo

Exu olafé, asseni bani darô

Exu iuô lo xe babalaô

Ojô metadinlogum lo gbe odô Oiá

Exu ma se mi omo elemirã ni o xe

Exu ma se mi lu enia ma se enia lumi

Ma jeki a rijá re

Iuô lo se iauô, ti fi ko okô re silê

Exu ma se mi, omo elomirã ni o se

Iuô lo se enia to fi binu soku

Iuô lo se enia to di ko sodó

Exu ma se mi, omo elomirã ni o se

Ibukum pupo ni emi fé lodô re

Eu iuô ni ilerá

Abô, egbegá, irê orô bem louô re

Jouô ki ouá fum mi ni nkã uoni

Exu Elegbara, gbo mi kiakiá

Exu ma se mi, omo elomirã ni ki o se

Axé."

Você também pode gostar