Explorar E-books
Categorias
Explorar Audiolivros
Categorias
Explorar Revistas
Categorias
Explorar Documentos
Categorias
01
Aráayé a je n’bo, Olúbàje a je n’bo
Aráayé a je n’bo, Olúbàje a je n’bo
Olúbàje a je n’bo, Olúbàje a je n’bo, Aráayé
02
È é é ajeniníiyá, ajeniníiyá
Àgò ajeniníiyá
Máà kà lo, ajeniníiyá,
Ajínsùn aráaye, ó ló ìjeniníiyá
E wa ká ló
Sápadà aráaye, ló ìjeniníiyá,
E wa ká ló
Ìjeniníiyá aráaye
03
Opeèré má dó péré
Ó bèré ké se
Má dó há, má dó pèré
Opeèré má dó péré
Ó bèré ké se
Má dó há, má dó pèré
Opèré má dó péré
Dó sú, màá dó é
Dó sú, màá wa dó, Dó sú màá wa dó
Dó sú, màá we n’gbé
Ayò kégbe hún hún
Ayò kégbe hún hún
04
Omolú Kíí bèrú jà
Kòlòbó se a je n’bo
Kòlòbó se a je n’bo
Kòlòbó se a je n’bo
Aráayé.
05
Ágò n’ilé, n’ilé
N’ilé ma dàgó
Sápadà, A jí nsún,
Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
Permissão (licença)
Para entrar na casa.
Licença Sapatá
Ajinsun, permissão
Para entrar na casa, licença.
06
Ó gbélé ìko, sàlàrè
Sálà rè lórí
Ó gbélé ìko, Ó gbélé ìko
Sálà rè lórí
07
Olórí ìjeníiyà a pàdé
Olorí pa
Olórí ìjeníiyà a pàdé
Olorí pa
08
Jó alé ijó, é
Jó alé ijó, é jó alé ijó,
Àfaradà a lé
Njó ó n'gbèlé
09
Àká ki fàbò wíwà
Àká ki fàbò wíwà
Wáá kalé, wáá
Kalé sé awo orò
Wáá kalé, wáá
Kalé sé awo orò
11
Ò ní a ló ìjeníìyà
Ajàgun tó ló
Ìjeníìyà Olúwàié
Táálá bé okùnrin
O táálá bé okùnrin
Wa ki ló kun
Táálá bé okùnrin
Abénilorí ìbé
Rí ó ní je Olúwàié
Táálá bé okùnrin
12
Wúlò ní wulò
A n'ilè gbèlé ibé kò
Wúlò ní wulò
A n'ilè gbèlé ibé kò
14
Onilè wà àwa lèsé òrisá
Opé ire onílè wà a lèsé òrisá Opé ire
E kòlòbó e kòlòbó sín sín sín
Kòlòbó
E kòlòbó e kòlòbó sín sín sín
Kòlòbó
15
Omolú pè olóre a àwúre e
Kú àbó
Omolú pè olóre a àwúre e
Kú àbó
16
Jé a n’penpe e ló gbé wàiyé
Tó ní gbón mi
Jé a n'penpe
Omolú wàiyé (Obalúwaiyé)
Tó ní gbón mi ó
17
Sé ó gbèje
Awo Kóró nló awo, kóró nló
Sé ó gbèje
Awo Kóró nló awo, kóró nló
Sé ó gbèje
19
Òdí Nàná ni ewà
Léwà lèwá e
Òdí Nàná ni ewà
Léwà lèwá e
Nàná ayò
Àwa ló bímon ayó alóko
Nàná ayò
Àwa ló bímon ayó alóko
Nanã Olocó (aquela que tem poderes para chamar um parente morto)
Faça-nos felizes; nós poderemos tomar outra direção para termos a
Alegria do nascimento de filhos.
Naná Olocó, faça-nos felizes.
Ò iyá wa òré, Ò ní aijalòòde
Ò iyá wa òré, Ò ní aijalòòde
20
Yemonja àwa, Ààbò a yó
Yemonja
Àwa ààbò a yó
Ìyààgbà ó dé iré sé
A kíì e Yemonja
A koko pè ilé gbè a ó yó
Odò ó fi a sà
Wè rè ó
A sà wè lé ó
Odò fi ó
A sà Wé lé ó
A sà Wè lé ó
Nós escolhemos nos banharmos
Em nossa casa.
Ela costuma escolher
Banhar-se no seu rio.
Ìyá kòròba
Kòròba ní sàbá
Ìyá kòròba
Kòròba ní sàbá
21
Oya balè e Láárí ó
Oya balè
Oya balè e Láárí ó
Oya balè
Àdá máà dé f´àrá
gè ngbélé
Oya balè e Láárí ó
Ó ní lábá-lábá - Ó lábá ó
Ó ní lábá-lábá - Ó lábá ó
22
Èyin rí àwa
ìgbàgbó wa okòn
Èyin rí àwa , ìgbàgbó wa okòn
Ètùtù sé ipadé siré
Kò rú lé, kò rú lé,
Bàbá Ifá
E sìn sé ipàde siré
Kò rú lé, kò rú lé,
Bàbá Ifá
Àjàlá mo rí mo rí mo yo
Álá forí kòn
E àgó fi rí mi
23
Ojó mò tyìn odó aláyé ojó
Ojó bí walé ojó
Ojó mò tyìn odó aláyé ojó
A bo wa Bàbá ó