Você está na página 1de 5

Nj O Ti Gb Nipa fin Mrin Ti Emi?

Have You Heard of the Four Spiritual Laws?


Just as there are physical laws that govern the physical universe, so are there spiritual laws which govern your relationship with God.
Bi ijba wa ti ni awn ofin lati bojuto alafia ilu, bni Olrun ni awn ofin ti a nilati m, bi a ba f ni alafia plu

God LOVES you and offers a wonderful PLAN for your life.

lrun FRAN r, O si ni ETO rere fun aye r

This is

GODS LOVE

IF LRUN

Eyi ni

God so loved the world that He gave His one and only Son, that whoever believes in Him shall not perish, but have eternal life (John 3:16 NIV).
And

"Nitori lrun f araiye to b g, ti o fi mo bibi r kanoo funni, ki nikni ti o ba gb a gb m b segb, sugbn ki o le ni iye ainipkun" (Johannu 3:16).
Ati

GODS PLAN

[Christ speaking] I came that they might have life, and might have it abundantly (John 10:10) [that it might be full and meaningful] .
Why is it that most people are not experiencing the abundant life?

ETO LRUN

[Kristi wipe] Emi wa ki nwn le ni iye, ani ki nwn le nii lplp (Johannu 10:10). [Itum eyi ni: Igbesiaiye kikun, ti o ni tlrn].
Ki ie gbogbo enia lo ngbe igbesiaiye to kun to si ni tlrn nitoripe

Man is SINFUL and SEPARATED from God. Thus, he cannot know and experience Gods love and plan for his life.

Awa enia j L, a si ti YAPA APA kuro ld lrun, nitorina a ko le m if lrun, bni a ko le ni rr eto r fun igbesiaiye wa.

MAN IS SINFUL

ENIA J LS

All have sinned and fall short of the glory of God (Romans 3:23).
Man was created to have fellowship with God; but, because of his stubborn self-will, he chose to go his own independent way, and fellowship with God was broken. This self-will, characterized by an attitude of active rebellion or passive indifference, is an evidence of what the Bible calls sin.

Gbogbo enia li o s ti s, ti nwn si kuna ogo lrun (Romu 3:23).


lrun da enia ki a le ni irp tmtm plu R; sugbn awa enia yn lati b Ona tiwa l, irp plu lrun si ja. Tt si na ti ara wa ibase ninu ohun kekere tabi ohun nla j s. r lrun lo s b.

"We all, like sheep, have gone astray, each of us has turned to his own way" Isaiah 53:6)

"Gbogbo wa ti sina kkiri bi aguntan, olukuluku wa tle na ara r" (Isaiah 53:6)

Yoruba/ English Edition - Page 1

MAN IS SEPARATED

IYAP WA APA IYAPA WA L'ARIN ENIA ATI LRUN

The wages of sin is death [spiritual separation from God] (Romans 6:23).
This diagram illustrates that God is holy and man is sinful. A great gulf separates the two. The arrows illustrate that man is continually trying to reach God and the abundant life through his own efforts, such as a good life, philosophy, or religion but he inevitably fails.
HOLY GOD

"Nitori iku li re " [Itum eyi ni, iyapa ti mi kuro ld lrun] (Romu 3:23)
Aworan yi fihan wipe, nitori lrun j mim enia j ls, iyapa nla w lrin awn mejji. Aworan yi se apejuwe pe enia ngbiyanju lati de d lrun. A lero pe bi a ba s sin dada, tabi ki a j enia rere, ki a ma gbadura, ki a ma l si ile lrun (i), bi a ko ba se ibi si nikeji wa, ati bb l, a o de d lrun. ugbn asan ni gbogb iyanju yi.

LRUN MIM

SINFUL MAN AWA ENIA ELEE

The third law explains the only way to bridge this gulf...

Ofin kta ntka si n kanoo ti a le gba pada s'd lrun

Jesus Christ is Gods ONLY provision for mans sin. Through Him you can know and experience Gods love and plan for your life.

Nipas Jesu Kristi nikansoso ni a le de d lrun. O ku fun wa. Nipas Jesu nikan ni o le m if lrun. Iw y si ni iriri eto lrun ni igbesiaiye r.
WA O KU DIPO WA

HE DIED IN OUR PLACE

God demonstrates His own love toward us, in that while we were yet sinners, Christ died for us (Romans 5:8).
HE ROSE FROM THE DEAD

ugbn lrun fi if On papa si wa han ni eyi pe, nigbati awa j ls, Kristi ku fun wa (Romu 5:8)
O JI DIDE NINU OKU

Christ died for our sinsHe was buried He was raised on the third day, according to the Scriptures. (1 Corinthians 15:3,4).
HE IS THE ONLY WAY TO GOD

Kristi ti ku nitori s wa a sinku r O jinde ni ij kta ggbi iwemim ti wi (Korinti 15:3-4)


JESU NI NA KANOO N

Jesus said to him, I am the way, and the truth, and the life; no one comes to the Father, but through Me (John 14:6).
This diagram illustrates that God has bridged the gulf which separates us from Him by sending His Son, Jesus Christ, to die on the cross in our place to pay the penalty for our sins.
lrun HOLY GOD

Jesu wi fun u pe, Emi li na, ati Otit ati iye: k si nikni ti o le w sd Baba, bikose nipas mi (Johannu 14:6).
Aworan yi fihan wipe lrun nikan ni o le mu wa pada sd ara R. lrun se eyi nipa riran Jesu Kristi lati ku ni ori igi agbelebu fun wa.

J E S U

SINFUL MAN ENIA

It is not enough just to know these three laws

ugbn ko to fun wa lati m awn ofin m ta yi nikan

Yoruba/ English Edition - Page 2

We must individually RECEIVE Jesus Christ as Saviour and Lord; then we can know and experience Gods love and plan for our lives.
WE MUST RECEIVE CHRIST

Eni kkan wa ni LATI gba Jesu LATI Kristi ni Olugbala ati Oluwa. Nigbayi ni a to le m if lrun, ti a si le ni iriri eto r fun igbesiaiye wa.
A NI LATI GBA KRISTI NIPA IGBAGB LATI NIPA

As many as received Him, to them He gave the right to become children of God, even to those who believe in His name (John 1:12) By grace you have been saved through faith; and that not of yourselves, it is the gift of God; not as a result of works, that no one should boast (Ephesians 2:8,9).
WE RECEIVE CHRIST THROUGH PERSONAL INVITATION

Sugbn iye awon ti o gba a, awn li a fi agbara fun lati di m lrun, ani awn na ti o gb oruk r gb. (Johannu 1:12). Nitori ore-f li a ti fi gba nyin l nipa igbagb ki ie nipa i ki nikni m ba ogo. (Efesu 2:8,9).

LATI NIPA WA A NI LATI GBA KRISTI NIPA PIPE E FUN ARA WA

[Christ speaking] Behold, I stand at the door and knock; if any one hears My voice and opens the door, I will come in to him (Revelation 3:20).
Receiving Christ involves turning to God from self (repentance) and trusting Christ to come into our lives to forgive our sins and to make us what He wants us to be. Just to agree intellectually that Jesus Christ is the Son of God and that He died on the cross for our sins is not enough. Nor is it enough to have an emotional expereince. We receive Jesus Christ by faith, as an act of the will. These two circles represent two kinds of lives: SELF-DIRECTED LIFE Self is on the throne. Christ is outside the life. Interests are directed by self, often resulting in discord and frustration

[Kristi wipe] Kiyesi i, mo duro li enu ilkun (kan r), mo si nknkun, bi nikni ba gb Ohun mi, ti o si si Ilkun, emi o si wle t wa (Ifihan 3:20).
Itum gbigba Kristi ni wipe, ki a ni igbkl ninu lrun lati wa si inu igbesiaiye wa, ki O si dari s wa j wa; ki a yipada kuro ninu s wa, ki a si j ki Kristi wa gbe igbesiaiye R ninu wa.

Awn aworan meji yi nse apejuwe orisi igbesiaiye meji: IGBESIAIYE ENI TI NE AKOSO ARARE N

Y S

Eni yi ndari aiye ara r. Kristi () wa lode aiye yi. Awn m dudu yi, duro fun orisirisi nyn igbesiaiye yi, ggbi, sn, owo, s, sro, ati bb l ti ni yi ndari. ugbn sibsib ni yi ko ni ifkanbal t p. IGBESIAIYE TI KRISTI NSE AKOSO RE BESIAIYE

CHRIST-DIRECTED LIFE Christ is in the life and on the throne. Self is yielding to Christ. Interests are directed by Christ, resulting in harmony with God's plan.

Nibiyi, Kristi () ti w inu igbesiaiye ni yi lati dari r. ni yi jw aniyan aiye r fun Kristi lati dari aniyan ggbi, sn, owo, s, sro, ati bb l. Eni yi ni ifkanbal plu lrun. A woran wo lo j igbesiaiye r? Aworan wo lo fe ki igbesiaiye r?
Eyi ni ly bi o ti se le gba Kristi

Which circle best represents your life? Which circle would you like to have represent your life? The following explains how you can receive Christ...

Yoruba/ English Edition - Page 3

YOU CAN RECEIVE CHRIST RIGHT NOW BY FAITH THROUGH PRAYER God knows your heart and is not so concerned with your words as He is with the attitude of your heart. The following is a suggested prayer:

O LE GBA IGBAGB

KKRISTI

NISISIYI

NIPA NIPA

Lord Jesus, I need You. Thank You for dying on the cross for my sins. I open the door of my life and receive You as my Savior and Lord. Thank You for forgiving my sins and giving me eternal life. Take control of the throne of my life. Make me the kind of person You want me to be. Amen.
Does this prayer express the desire of your heart? If it does, I invite you to pray this prayer right now, and Christ will come into your life, as He promised. Did you receive Christ into your life? According to His promise in Revelation 3:20, where is Christ right now in relation to you? Christ said that He would come into your life. Would He mislead you? On what authority do you know that God has answered your prayer? DON'T RELY ON FEELINGS Thank God often that Christ is in your life and that He will never leave you (Hebrews 13:5). You can know on the basis of His promise that Christ lives in you and that you have eternal life from the very moment you invite Him in. He will not deceive you. The moment that you received Christ by faith, as an act of the will, many things happened, including the following: 1. Christ came into your life (Revelation 3:20). 2. Your sins were forgiven (Colossians 1:14). 3. You became a child of God (John 1:12). 4. You received eternal life (John 5:11-13) 5. You began the great adventure for which God created you (John 10:10, 2 Corinthians 5:17).

O le gba Kristi ni Olugbala ati Oluwa bi o ba gbadura pe ki Kristi w inu igbesiaiye r wa. Ki o ni igbagb pe yio wa. Adura yi ni lati j tkantkan. lrun m kan r, o ko si le tan A j. Gba iru adura bayi:

"Jesu Oluwa, mo m wipe emi ni mo ti ndari aiye mi. Nitori eyi, mo ti ds si . Jw wa sinu aiye mi, wa dari mi j Wa mi. Wa e Alakoso igbesiaiye mi. S mi di ni mim. Mo dup pe, O ti gb adura mi. Amin.
Nj o f lati gba adura yi? Bi o ba f b, gba adura yi nisisiyi, Jesu yio si wa sinu igbesiaiye r ggbi O ti e ileri. Nj o ti gba Kristi sinu aiye r? Bawo ni o e m? Boju wo hin lati ri ileri Kristi ni Ifihan 3:20 A le m wipe Kristi wa ninu aiye wa nitoriwipe Kristi e ileri lati w. O k tun ni lati pe Kristi wle m. MAE GBOJULE ERO KAN RE Inu r le dun Ioni, Kristi yio si wa sinu igbesiaiye r. Kristi wipe, Emi ko j fi sil (Heberu 13:5). K lati ma gbkle awn ileri lrun, ma gbkle ero kan r.

Nigbati o gba kristi plp nkan ni o l Di ninu wn niwnyi:1. Kristi wa si inu igbesiaiye r (Ifihan 3:20) 2. A dari r ji (Kolose 1:14). 3. O di m lrun(Johannu 1:12). 4. O ni y ainipkun (1Johannu 5:11-1 3). 5. O br si ni iriri igbesiaiye titun ti o ni itlrun bi kKristi ti ngbe igbesiaiye R ninu r (Johannu 10:10; 2 Korinti 5:17). p lr bayi ati ju b l lati inu r lrun ni nwn je tir. Y nwn wo ninu Bibeli. Ni Ise-AwnApsteli 17:11 nwn ny Iwe Mim w lojojum "bi nkan wnyi ri b.

Can you think of anything more wonderful that could happen to you than receiving Christ? Would you like to thank God in prayer right now for what He has done for you? By thanking God, you demonstrate your faith.

Yoruba/ English Edition - Page 4

SUGGESTIONS FOR CHRISTIAN GROWTH Go to God in prayer daily (Luke 18:1). Read Gods Word daily (Ps 119:11); begin with the Gospel of John. Obey God moment by moment (John 14:21). Witness for Christ by your life and words (Luke 18:39). Trust God for every detail of your life (1 Peter 5:7). Holy Spirit - allow Him to control and empower your daily life and witness (Galatians 5:16,17; Acts 1:8).

IM IM RAN FUN IGBAGB

IDAGBEASOKE

NINU

Ma gba dura lojojum (Luku 18:1). Ma ka r lrun (Bibeli) lojojum (Orin Dafidi 119:11) Br si k lati inu ehinrere ti Johannu. Ma se igboran si lrun nigbagbogbo (Johannu 14:21). Ma jri fun Kristi nipa igbesiaiye r ati r nu r (Luku 8:39). Ma gbkele lrun ninu ohun gbogbo (1 Peteru 5:7). Ma je ki Emi Mim lrun ti O wa ninu r nisisyi dari igbesiaiye r. J ki O fun ni agbara lati jri Jesu (Galatia 5:16,17; Ie Awn Apsteli 1:8).

Gods Word instructs us not to forsake the assembling of ourselves together (Hebrews 10:25). Start going to church where Christ is honoured and His Word is preached. Start this week, and make plans to attend regularly. Why not share this message with someone else?

O se pataki pe ki o darap m awn onigbagb fun idagbasoke ninu igbagb r (Heberu 10:25). Br si l si ile lrun ti nwn ti mbu la fun Kristi, ti nwn si nwasu otit r R. Ko wa y ki o fi irohin ay yi l lomiran?

SPECIAL MATERIALS ARE AVAILABLE FOR CHRISTIAN GROWTH. If you have come to Christ personally through this presentation of the gospel, helpful materials for Christian growth are available to you. For more information write: Campus Crusade for Christ Australia, PO Box 40, Sydney Markets, NSW 2129 phone (02) 9748 5798 Fax: (02) 9748 5799 email: materials@hereslife.com Website: www.hereslife.com Campus Crusade for Christ Australia, 2002
A.C.N. 002 310 796 Item: YorEng4pWBw05Apr

Campus Crusade For Christ ti Nigeria, PO Box 500, Jos.

Helping you reach multicultural communities with the Gospel


Yoruba/ English Edition - Page 5

Você também pode gostar