Of, enquanto os inimigos beberem gua no conseguem atacar a essa pessoa, e se
persistirem em fazer mal, morrem. risca Odu Ogbe Meji no ierosun e recita o ofo em cima, com um copo de gua ao lado, depois de juntar o p, mistura com a gua e bebe tudo, no pode sobrar nada.
OMI LA NI NSOJU REGUREGU IDA NLA MADE DEREDERE
AWON LO SE IFA FUN OKUNRIN RORO O NSAWO LO SADE APATO WON NI AWON OSO TO NBE NIBE, NKO WON NI AWON OSO TO NBE NIBE, WON KI NJE KI WON NI OWO RARA WON KI AWON AJE TI WON NBE NIBE WON JI NJE KI WON BIMO OLOGUN TI NBE NIBE PIPA NI WON NPA WON PA ENIYAN WON NI AWON BABALAWO TI WON NBE NIBE, WON JI NJE, KI WON KOLE, ORUNMILA NI IRO NIWON NPA, IFA NI ISOJU AHAN NI EYIN SE NYO, ISOJU AHAN NI EIYN SE NTAN, ALAJA OUN NI OKO NLA OMI, GBOGBO ENI BA NPERI MI NIBI, EJI-OGBE A MAA BA MI KO, WON LO SODE ORUN, ORUNMILA WA SE ENU KOTO, ESU FI ORIN AWO SI LENU.
ALOJA NI ALAKO NLA OMI (repete duas vezes cantando)
EMI........................MAA LA IGA TEMI JA
(.......) pe o nome da pessoa que vai beber a gua.