Você está na página 1de 1

OGUN IFERAN

Gbogbo nkan lalelofun

Ewe omisimisi gogoro ati pelebe, gilasi tiwan nfi wo oju dada, koro sugar meta ao lo kuna dada
ao teni eji ogbe ao pe ohunre si ao da sinu oyin ao mala

Eleri ikan 3x Aba orisa 3x Amunidele ire 3x Arile rere yasi woni lewu ola 3x,

Awon mererin niwon da ifa fun orunmila nigbati ifa nlo ba olokun sore 3x won ni olokun ma
binu siyan ni 3x orunmila ni olokun koni binu si ohun, won ni ibinu omo araye nko, orunmila ni
koni binu si omo araye, oni nitoripe oba ilu kibinu oba ilu, oba osin kibinu oba osin, Oba Ajalaye
kibinu Oba Ajalawarun, Oba ajalawarun kibinu oba olomerenmere, Oni bi omode bawo digi
arerin bi agbalagba bawo digi arerin, nitori adun duntan niti ewe omisimisi ndun kan araWon,
Adun denu ni sugar ndun, omode ki fi oyin senu ki opose, Agbalagba kifi oyin senu ki opose,
EJIOGBE gbe ife mi si okan(nome da pessoa que se quer)tabi gbogbo araye ki o fi ife aje sin mi

Vai pegar duas colheres de açúcar por em uma panela e marcar ejiogbe fazer o ofo

Vai colocar as folhas o mel e cozinhar

Depois tem que se olhar no espelho da mistura e fazer seus pedidos de amor e consumir

Obs: na parte final do ofore OKAN.... TABI pode se ñ colar nome de ninguém e so colocar OKAN
MI GBOGBO que todos me amem .

Você também pode gostar