Você está na página 1de 12

(Odu ifa obara bogbe, is fou arebi iwure.

) Iku yoo, arun yoo, adifa fun, won ni ode ido, omo atan ina, ifa
roro le iku loo, nje iku ti nbe ni ode leyi koderu koma loo, owiriwiri, ao fi ina ifa wi won laraa, gbogbo ajogun
ti nbe nile yii, ko deru komo loo, owiriwiri, ao fi ina ifa wiwon lara, ki ifa segun fun wa, lori omo lori iyawo
ebi ara. Ase waaaaa.

isegun awon ota

(Odu irete iwori)

atepa iwori, Babalawo erin lodifa fun erin, erin sawo roke alo, nje itakun kan itakun kan toni kerin mo dalo
atohun aterin ni njonlo, erin afi se ojade afi se oko jaje, eniyan kan eniyan kan to ni kebo mose daa,
atohun atebo ni jo nloo, yoo bebo loo, kosai bebo loo, enipe bo moda, kosai bebo loo, lese Obarisa. Ase
waaaaaaaaa.

Ifa irosudi.

Atelewo niko yangan ni joo, eyin owo lodun yan paa, ola ni ija akan, bi alakan bajeun to bayo, afi owo
agada ba omi tetete, adifa fun, aayo, ti n ko omo re rejo, adifa fun aasun, ti ko omo re rejo, awon erigi
yanda, loki fafun Orunmila Baba nje laarin ota, ebo ni won ni ki ose, nje aayo waapaa oka, aasun sun paa
eree, awon alade yi pepe potare ko fi idi paa ina iku, arun, ofo, ija, gbogbo ajogun fun wa oooo.
 1. Omimimo rubo - primer acto ritual de libacion para purificar el house

Ìdà kí si ònà ni nse ejò lè yín A d’ífá fún Esin ohun Àgbò Tí í wòn nse awo losí ilé oní alákétu
Njó tó jí ti kò ojúnbà Bàbá Tí kò ojúnbà yèyé Ìbà bàbá Ìbà olówò Ìbà ojùgbònà Ìbà àwon àgbà
awo Ìbà apásá pà aso má n rò ó Ìbà ó kú tè gbogbo a rò so má ojúnbà Aya má n fohun
táábadase Koro ma n saìgbá Àse

que enlazo con esto


agbara nla ni yabe si poro oko A difa fun iba to n somo Olodumare Gbogbo awo isope Gbogbo
ara (nome de su templo espiritual) E je a maa juba a to n sawo
asre
agora se activa ase de omi asi

Ka ta sile ka ta senu Ka ma je tile poju tenu A difa fomo Tii segbon ire Ki la nta sile ka to wure ?
Omi la nta sile ka to wure Ase
continuo ahora con
un ese de omimimo rubo
que es asi
eruku lele ori ogan a difa fun ekolo ti nse omo aja niwa orun Bi ekolo ba juba re ile alanu Ase o

ose tuura es eso


el ese dice asi
el fino polvo en la colina Lanzó ifa para el gusano de tierra que es hijo de aja en el cielo Si el
gusano de tierra rinde pelitesia a su padre, la tierra se abre
ahora los 3 ese son de odu diferentos

agora toma su dedo medio e voy asi en la tierra

omi tutu (x3) Ona tutu (x3) Ile etigbere abeni ade tutu (x3) Ilemole .... (nome de su templo) tutu
(x3) Tutu babanla TUtu Orí (se pasa pelo frente ate nuca agua e de tudos los presentes en su
caso) TuTu emi tutu Elegba tutu igbamole tutu irunmole tutu orisa tutu eborakebora tutu isoro
orun tutu esiba orun tutu egungun kiki egungun tutu aye

en cada tutu (vierte agua en lo suelo)

agora pide para que no manifestase en su vida el dia mesmo


lo seguinte
Ko si iku Ko si arun Ko si ejo Ko si ija Ko si ofo Ko si epe Ko si ewon Ko si egba Ko si oran Ko si
aisan Ko si aisian Ko si aisise Ko si wahala Ko si fitigbo Ko si rudurudu Ko si idina Ko si ailera
Ko si ailoro Ko si aleso Ko si akoba Ko si aselu Ko si olopa Ko si asasi Ko si egun Ko si egun
buruku Ko si oogun ika Ko si ika eni Ko si elenini Ko si ajogun Ko si ota Ko si ailowo Ase ariku
babawo

generalmente aqui uso un ese de oturupon di


para alejar evil spirits
oturupon di eye si oturupon di eye ba oturupon di eye si eye o si oturupon di eye ba eye o ba
Oturupon di eye ni o ta kankan ko gun'gi Difa fun Orunmila Ni'jo awon eleye ile iya re rrran ni wa
pee Aje ile, oso ile e m'owun mi Eleye kii ba eleye wijo Ase
e uso junto outro de ogunda owonrin para atraer energio de forzas primordiales e mis ancestros

Okun kun nore Osa kun legbe legbe Olowa nr'owa alasan nr 'asan Agba imole wo eyin oro, o ri
pe ko sunwon O fi irunmu d'imu yayaya O fi irungbon di aya pen pen pen Difa fun Isese merin Ti
won nse olori ori n'Ife Nje, kinni a ba bo n Ife?? Isese ni a ba bi, ki a to bo Orisas Baba eni ni
isese eni Iya eni ni isese eni Ori eni ni isese eni Ori egun eni ni isese eni Egbe orun eni ni isese
eni Ikin eni ni isese eni Odumare ni isese Isese mo juba ki nto sebo Ase

aqui concluye el omimimo rubo


aqui comenzo con Eledua

1. Fi ase pe Eledua 2. Ikin 3. Ijuba 4. Oriki 5. Iwure


Ase ase o Ase fun o Ase Olodumare yio ba o gbe laye
Olodumare mo pe o (x3) Mo pe o sotito sododo Mo pe o iwa pele Mo pe o iwa rere Mo pe o iwa
Mo pe o sawo Mo pe o (lo que usted quieras) ......... Wa de de wa Olodumare (x3) ase
MO juba re Olodumare (x3) Mo juba eleda mi Pele o eleda mi Eni rowo mo ba Eni ko rowo a ja
Wara wogbo lo Ase
Mo ji mo ki Arugbo ojo, eleda mi Olodumare (x3) Ji ooooooo Ejire oooo Mo ji mo ki ooo Mo ji mo
ki eleda mi Ase
tengo las lamanos abertas a lo ceu tudo lo tiempo
Iba'se Olodumare oba ajiki mo ji loni mo wogun merin aye Iba'se odo ede onibode ile oba
edumare Mo juba re loni, maa jeki mi soni soro
Atiwaye ojo Iba lowo re Atiwo oorun Iba lowo re Iba Olodumare oba aseda aye, oba aseda orun
Oba wole wole Tii wo inu opolo Oun l’Oyeye tii ye Inu okan Eda wo Mo juba re loni maa je ki mi
so ni soro
Antes de comenzar con el Ijuba
agradezo
Ope ni fun Olorun Mo dupe o (x3) Mo dupe lowo yin o Eledua Por un nuevo amanecer, etc...

Iwo ni oluwa olorun mi o Iwo ni eleda mi Oba mi adigun Olorun oba mi Oju re wa o
agora oriki
Eleda, elemi, olojo oni, kodenlege, aterere kari aye awusikatu, oba a joko, birikitikale alaburkuku
ajimukutuwe ogiriba jigbo bi ti o fi imole se aso bora, oludare ati oluforigi, adimula, olofin aye ati
orun, a fun wen ake wen, Owenwen ake bi ala. Alate ajipa Olofa oro Oba a dake dajo. Awosu sekan.
Oba ajuwape alaba alase lori ohun gbogbo. Araba nla ti nmi igbo kijikiji. Oyigiyigi Oba akiku ati Oba
nigbo, Oba atenile forigbeji, Awamaridi Olugbhun mimo to Orun. Ela funfun gbo o Oba toto bi aro,
pamupamu digijigi ekun awon aseke. Awimayehun Olu ipa Oba Airi. Arinu rode Olumoran okan.
Abowo gbogbogbo ti yo omo re. Ninu ogin aiye ati Orun. Iba to – to – to. Asè.

 Olodumare oba ajiki Edumare oba ajige Ogege to ba gbe ile aye duro Ogbagba nla oba
to lode orun Baba awa omo re la n pe o Lati wa gba ire tiwa Olodumare tati were ki o wa
gbahun awa omo re Bi o ba gbo ki o muu se Ibi kibi ti aba nlo maa jeki a bo sowo iku Gbogbo
ojumo tobi ti nmo ire ni ko maaje fun wa Maaje ki Esu o bawa ja Abe o loruko Orisa akunle bo
Ati loruko Orisa abere bo Ati loruko Orisa aduro bo Ki aabo re eti iranwo re o maa bawa gbe ni
gbogbo ojo Ki o se bee ! (x3) Ela iboru Ela boye Ela bosise

 su iwure

Olodumare awa omo re de Ade lati wa gba ire tiwa Asin nbe o loruko odu merindinlogun Ki o
gbo ire toni yi Bi o ba gbo ki o muu se Ki o maa so baba wa Ki o maa so iya wa Ki o maa so aya
wa Ki o maa so omo wa Ki o maa so agbagba wa Ki o maa so alabaa gbele ati ore wa Titi tofi
mo ibi ti ani eni de Paapaa ati awon molebi wa Afi olojo oni be o Ki o fi ye denu Ki o fi ye dekun
Ki io fi ye de gbogbo ara Baba awa omo re la n pe o Ela Iboru Ela boye Ela bosise

Olodumare so wa di nla Ela omo osin so wa di nla Orunmila so wa di nla Olodumare wa fi mi se olu
A kii mu ewe oye miran lehin koko Iba iba ooo Agbelegbola (x3) Agbodedegbayi (x3) ase

3
fifun mi ni itona e fifun mi ni aabo e finfun mi ni ase e
proveame = fifun mi ni
itona = guia/directriz aabo = proteccion
ahi pode usar tanto cosa como ud gustas

 cuando esta en un apuro


pode agregar un iwure
especial
para eledua
de ose bi sile

Difá fún Òrúnmìlà Bàbá nse ohun gbogbo Tí òkan kó yanrí Wón ní kó lo fi Olórun rè se bàbá
………………………. Gbà mí o Olórun mí gbà mi o Ìwo ni mo sá di Ìwo ni mo gbíyè mi lé Ìwo ni
fèyin tì Enikan kìí fèyin tì Olórun Gbà mí o Kó dójú ti ni Gbà mí o Olórun gbà mí o Olórun mi gbà
mi o Ìwo ni mo fèyin tì Gbà mí o Olórun mi gbà mí o Kò pé kò jìnnà Ire gbogbo wá ya dé tùtúru
Receive me/accept me Lord of heaven accept/receive me Your are the chosen one to cover me You
are the chosen one on whom I can depend on You are the chosen one to be the pillar on which I
sustain myself Whoever can depend on Olórun Receive/accept me Pick me up/ be my pillar
Receive/accept me My God receive/accept me You are the pillar on which I lie Receive/accept me
My God receive/accept me After a time, no long All blessings will come out from you.


 Olodumare oba ajiki Edumare oba ajige Ogege to ba gbe ile aye duro Ogbagba nla oba to
lode orun Baba awa omo re la n pe o Lati wa gba ire tiwa Olodumare tati were ki o wa gbahun
awa omo re Bi o ba gbo ki o muu se Ibi kibi ti aba nlo maa jeki a bo sowo iku Gbogbo ojumo tobi
ti nmo ire ni ko maaje fun wa Maaje ki Esu o bawa ja Abe o loruko Orisa akunle bo Ati loruko
Orisa abere bo Ati loruko Orisa aduro bo Ki aabo re eti iranwo re o maa bawa gbe ni gbogbo ojo
Ki o se bee ! (x3) Ela iboru Ela boye Ela bosise

este outro iwure que pode adicionar se ud acostumbra habar con dios
jjejeje

ahi termina cosa con eledua


hago despues Ori
el ikin es el mesmo somiente cambiando parte de eledua por ori

 agora es ori
tomando agua del recipiente mesmo

15:54

Nico Bonc

iba'se lodo apere mi ooo Ori oto sii ni sin ori apere Ori olowe akeke lube Ori mi sin mi Eda mi
sin mi re ooo Gbogbo ibi ti aba nlo laye po Ori ko dakun koba mi lo Atari boba sin mi titi Ma pa
da le yin mi ooo Iba ase Ori inu mi Iba ase Iponri ti o wa lorun mi oooo Mo juba re loni maa je ki
mi so ni soro

15:54

Nico Bonc

con manos en cabezo


suelo rezar asi
Mo su re fun Ori Jeki ori mi a gbe mi Jeki mo ri rere orisa mi Mo su re fun Ori Ase
Ori wo ibi ire (Orí place me in good condition) ki o gbe mi de (My feet, carry me to where condition is
favorable) Ese wo ibi ire (Where Ifa is taking me to, I never know) ki o sin mi re (Casted Ifá for
Sasore) Ibi ope agunka ngbe mii re (In the prime of his life) Emi ko mo ibe (If there is any condition
better than the one I am in) Difa fun Sasore (at present) Eyi to ji ni Kutukutu owuro (May my Ori not
fail to place me there) Nje ti o ba tun ku ibi to dara ju eyi lo Ori mi ma sai gbe mi de ibe. Ase

Orí mi gbe mi (Support me my Ori) Ori mi la mi (Make me prosperous, my Orí) Gbemi atete niran
(Orí is humankind’s support prior to any Orisa) Gbemi atete gbeni ku foosa Ori nii gbe mi Ajawo, kii
se oosa Ori inu ma ba to de je (Inner head please do not spoil the external head) Ase

 son los ancestros

15:59

Vinny Romanelli

ok

15:59

Nico Bonc

Akisale (x3) Etigbure (x3) Ile mo pe (x3) Oro mo pe (x3) Ori Egun mi mo pe o (x3)

antes
el fi ase pe egungun
ase ase o ase fun o ase ori egun mi yio ba o gbe laye
cuando ud hace lo de akisale, etigbure
se faz circulo con mano izquierda como se estivesse agraando algo
e glopea con dedos medio de mano derecha
es para chamar el spirit
oro mo pe (spirit i call upon you)
akisale the spirits of the upper heaven
cuando esta en parte de ile mo pe o
tene que tocar la tierra con esos dedos que uso de manera derecha
el ijuba para egungun
comenza sempre con Iyami Osoronga
quien faz possivel comunicacion con egungun

On Òrìsà worship – small document


It’s extremely condensed to make it as simple as posible for you in the beginning
Orí

In sitting position, take your head with your hands and say:

Ase ase o
Ase Ori mi yoo ba o gbe laye

Akisalè (x3)
Etigbúré (x3)
Òrò mo pè (x3) (Spirit I call upon you)
Ilè mo pè (x3) (Mother Earth I call upon you)
Orí mo pè ooo (x3) (My Head/Destiny I call upon you)

Put your mid finger in water and rub it in your head (de frente a nuca x3) saying:

Ìbà’se lodo apéré mi o (Homage to my Head/Destiny)


Orí oto sín ni sin orí àpéré (One’s head is what one worships)
Orí olowe akeke lube (The head is what the prosperous worships)
Orí mi sin mi (My Head please be with me)
Èdá mi sin mi re o (My guide please be with me)
Gbogbo ibi ti aba nlo laye po (May I find no ibi in my path)
Orí ko dakun ko ba mi lo (Wherever I go please be with me)
Atari boba sin mi titi (Always be with me)
Ma pada leyin mi o (Never turn away from me)
Ìbà’se orí inú mi (Homage to my spiritual/inner head)
Ìbà’se Ìponrí ti o wa lorun mi o (Homage to my spiritual counterpart)
Mo júbà re loni maa jeki mi soni soro (I pay homage to you so please do not let me find
difficulties on my way).

Ahora a couple of oríkì para tu destino:

Ori wo ibi ire (Orí place me in good condition)


ki o gbe mi de (My feet, carry me to where condition is favorable)
Ese wo ibi ire (Where Ifa is taking me to, I never know)
ki o sin mi re (Casted Ifá for Sasore)
Ibi ope agunka ngbe mii re (In the prime of his life)
Emi ko mo ibe (If there is any condition better than the one I am
in)
Difa fun Sasore (at present)
Eyi to ji ni Kutukutu owuro (May my Ori not fail to place me there)
Nje ti o ba tun ku ibi to dara ju eyi lo
Ori mi ma sai gbe mi de ibe.
Ase

Orí mi gbe mi (Support me my Ori)


Ori mi la mi (Make me prosperous, my Orí)
Gbemi atete niran (Orí is humankind’s support prior to any Orisa)
Gbemi atete gbeni ku foosa
Ori nii gbe mi
Ajawo, kii se oosa

Ori inu ma ba to de je (Inner head please do not spoil the external head)
Ase

At this point you can ask your head whatever you require from it. Orí is the most important
thing because it is your destiny that you are praising to manifest all good things.

Orí Egún

Ase ase o
Ase orí egún mi yio ba o gbe laye

Akisale
Etigbure
Òrò mo pè
Ilè mo pè
Orí egún mi mo pè e (x3)

Ìbà àse Ìyámí Òsòròngà opiki elese osun a jefun jedo


Enyin eleye agbalagba
Fi eje rofo
Iba ooo
Bàbá Egúngún Monriwo Ìbà (The divinity of the Ancestors, Homage)
Egúngún kiki Egúngun Ìbà (All masquerades, homage)
Enyin ará òrun kin in kin in gbogbo Ìbà (All heavenly being, homage)
Ìbà’se Egúngún Láyèwú (I pay homage to the masquerade of hunters)
Ìbà’se Egúngún Olóògùn (I pay homage to the masquerade of oloogun)
Ìbà’se Agan (I pay homage to the spirit of Agan)
Ìbà’se Òsé Òyèkú e nle o rami ooo (I pay homage to the sacred odù Òsé òyèkú that
allows the communication with the ancestors)

Ìbà’se Orí Egún mi (I pay homage to my ancestral lineage)


Ìbà’se Egúngún oloro mi (I pay homage to my male ancestors)
Ìbà’se Egúngún onijo mi (I pay homage to my female ancestors)
Ìbà mi dówó ilè tó ré koja si òrun (I pay homage to my human ancestors who went
to heaven)
Gbogbo Egún mi yin y’órun, òrun àyobò kú oru ìsàlè (My ancestors who dwell in heaven, the
good
and peaceful heaven, in the eternal night)
Ìbà (Homage)
Mo pè yin, enyin sá ni bàbá àti ìyá mí (I call upon you,who are my fathers &
mothers)
Èmi kò gbàdé yin ooo ( )
Enyin wá bá ni t’ójú egbe (you who have come to help the community)
Enyin wá lé ( )
Enyin dide kó yá ( )
Eyin ba ni m’egbe lówó
E tètè gbó’hun tí mo so
E báni t’egbe se, kó dára (Protect our community so all can be cool &
fine)
Ase te fun mi oun la nlo (I am using the ase you gave me)
Bi o ba si ato, se ki n d’omo (Sin el poder del semen, el óvulo no fecunda)
Bi o ba si ase, ato ki nd’omo (Sin el poder del óvulo, el semen no fecunda)
Emi l’ase enyin l’ato (Soy óvulo, ustedes el semen)
Emi l’ato enyin l’ase (Soy semen, usted óvulos)
Gbogbo yin ko ni je si ewu lona mi ooo (With your protection there is no danger in my
way)
Mo juba re egungun kiki egungun maa jeki mi soni soro (I pay homage to all masquerades,
allow
me to find no difficulties in my duties
today)
Fifun mi ni: itona e / aabo e / ase e / whatever you need to ask (Bring me your guidance,
protection,
ase,….)

Egbe

Ase ase o
Ase Egbe òrun mi ooo yio ba o gbe laye

Akisalè (x3)
Etigbúré (x3)
Ilè mo pè (x3)
Òrò mo pè (x3)
Egbe òrun mi ooo mo pè (x3)

Ìbà’se òrìsà olomoyóyó olomowéwé


Ìbà’se Egbe ògá ògo
Ìbà’se Eleriko
Ìbà’se Janjasa
Ìbà’se Oloiko
Ìbà’se bòròkìnní òrun
Ìbà’se bòròkìnní ayé
Ìbà’se Egbe òrun mi ooo
Awon egbe òrun Iba ooo

Ìsánsá méjì ní kira won jéé jèè jé (It’s 2 abscondees that great each other silently)
A dífá fún Egbé òrun (Casted Ifá for heavenly comrades)
A bù fún Egbé ayé (And also for earthly comrades)
Bòròkìnní òrun kì í jé táyé ó té (Heavenly comrades prevent those on Earth from
disgrace)
Bòròkìnní òrun e gbà wá (Heavenly comrades, come in our help)
Ti ayé n té lo (The ones on Earth are about to be disgraced)
Àse
Egbe ògá ògo (Egbe the great ones)
Alábénú à n sá sí (You under whose umbrella one seeks solace)
Atélésin tèlé (You who most of people reach and even follow)
Apò jojo bí èrùpè (You who are as many as sand grains)
Bòròkìnní òrun tí èé jé tayé ó té (Heavenly comrades who prevent disgrace for the ones on
Àse Earth)

Èsù Òdàrà

Ado isubi isure o


Ado isubi isure Èsù yio ba o gbe laye

Akisalè (x3)
Etigbúré (x3)
Ilè mo pè (x3)
Òrò mo pè (x3)
Èsù Òdàrà mo pè (x3)

Whistling now you say:

Èsù oloogbe
Egba oloogbe
Igoroko oloogbe

And ijúbà:

Ìbà’se Èsù láàlú ògiri òkò kiri ògo a ba eni wóràn bi a o ri dá


Mo júbà re loni máa jeki mi soni soro

Ìbà rabo o mo júbà (x3) (Oh great one I pay homage to you)
I ba kose omo deko (A young child does not approach Èsù)
Elégbára (x3) (The owner of power x3)
O mo júbà Èsù (Oh I pay homage to you Èsù)
Elégbára Èsù lonà (The owner of power, Èsù on the road)
Òdàrà kolori eni ijo (Òdàrà who has no head for dancing)
So so so abe (The sharp, stubborn knife)
Kolori eni ijo (Who has no head for dancing)
Èsù tiriri (Èsù the awsome one)
Bàrà abebe (The knife of power)
Tiriri lòna (The great one of the road)
Mo júbà Èsù (I pay homage to you Èsù)
Àse

Èsù mase pekun (x3) (Èsù don’t close the door on me) x3
Èsù jeki ahon mi (Èsù may my tongue be filled with)
Bara (x3) (power, power , power)
Jeki oro mi ni gba inu orun (May my words be received in heaven)
Àse
You can add as many prayers and wishes as you want.

Ifá

Àse ase o
Àse Ifá yio ba o gbe laye

Akisalè (x3)
Etigbúré (x3)
Ilè mo pè (x3)
Òrò mo pè (x3)
Ifá mo pè (x3)
Èlà mo pè (x3)
Òrúnmìlà mo pè (x3)
Ajagunmale mo pè (x3)
Àwon ojú odù mo pè (x3)

Ìbà’se Ifá ohun Olódùmarè


Ìbà’se Èlà
Ìbà’se Òrúnmìlà Elerìí Ipin Ibikeji Èdùmàrè
Ìbà’se Agbonmiregun oloja ori bojo
Ìbà’se Aladundun òrun
Ìbà’se osungaga opa oriri
Ìbà’se Ajagunmale olúwo òde òrun
Ìbà’se Aromoganyin onibode aye oun orun
Ìbà’se Awonamaja babalawo tii n komo nIfa oju orun
Ìbà’se Olótééréré, Olóyééréré, Akúndùngbèwa, Agbóròmafò, èjì olósùn, èjì ohenren, èjì òbàrà,
èjì òkànràn, èjì ògúndá, èjì osá, èjì ìkà, èjì ológbón, èjì òtúrá. Èjì èlèmèrè, èjì òsé,
èjì òràngùn, ohun òsé túúrá
Aseba lodu lodu toku ki ama se se oni soro
Ìbà Kutukutu awo owuro
Ìbà Ganrin ganrin awo osan gangan
Ìbà Winrin winrin awo oru
Ìbà Okuku suwiri oganjo
Ìbà Kòròfò awo aja ilè

Ìbà Afefelegelege awo isalu aye


Ìbà Efuufulegelege awo isalu orun
Ìbà Elewu ide awo òòrùn
Ìbà Elewu àlà awo òru
Ìbà Ìràwò sasa nbe lehin fÒsùpà
Ìbà’se àwon agba awo òrun
Mo júbà re loni máa jeki mi soni soro

Traducción (en orden):

Homage to Ifá; homage to Èlà (The Spirit of Purity); homage to Òrúnmìlà the witness of destiny
and second of Olódùmarè; homage to Agbonmiregun; homage to Aladundun òrun (the spirit of
the files of destiny); homage to Osun (the custody of ancestral memory/consciousness); homage
to Ajagunmale the priest of heaven, homage to Aromoganyin the gateman of the great beyond;
homage to Awonamaja the priest that teaches Ifá in dreams; homage to all 16 major odù Ifá and
all remaining ones; homage to Kutukutu the priest of the early dawn, homage to Ganrin ganrin
priest of the noon; homage to Winrin Winrin priest of the Night; homage to Okuku suwiri
oganjo priest of the midnight; homage to Korofo the priest of the underworld, homage to
Afefelegelege the priest of the Earth; homage to Efuufulegelege the priest of the Universe;
homage to the Elewu Ide the orisa of the sun; homage to Elewu Ala the orisa of the moon;
homage to Irawo sasa the orisa of the cosmic stars; homage to all departed elder babalawo – I
pay homage to you so please allow me to find no difficulties in performing my duties today.

Òrúnmìlà elérìn-ìpin, Aje ju gún, Ibi keji Olodumare akoko Olókun


Ajao ikoto ara Ado, ara Ewi, ara oke Itase, ara ojumo,
Ibiti ojo ti nmo, waiye ara oke l’geti okeje oje.
Erin fon olagilagi okunrin, ti nmu ara ogidan le, alakete pennepe,
Pari ipin, oloto kan to ku l’aiye, Oba iku ja gba omo re sile,
Odudu ti ndu or emere, ma ba jo otun ori ti, ko sun won se. Ase.

Orúnmila, dé testimonio de la Creación, proveedor de la medicina poderosa que está al lado de


la joya del océano.
Saludos al nativo de Ado, al nativo de Ewi, al nativo de la montaña, al nativo del alba.
El lugar donde llega el alba, el lugar donde el nativo del Cielo viene a la Tierra.
El elefante nos protege del mal de los hombres, es comprensivo y fuerte, y forma una calabaza
de luz blanca,
Las materias pequeñas se despliegan, un hombre honrado puede morirse en cualquier momento,
el jefe protegerá a los niños de la mandíbula de la muerte,
El poder que protege la cabeza de los espíritus elementales, nunca se vuelve menos que la
propia cabeza, porque es la fuente del poder. Asé.

Los rezos para Ifá te los proveeré en un libro especial que ya tengo impreso so you can choose
depending on what do you want.

Você também pode gostar