Escolar Documentos
Profissional Documentos
Cultura Documentos
#SISERE_ AO DUN IGUN YEN - SINU APE -TUNTUN- AOGBE OHUN NA SI- AOKO
ORI OKA SI- ORI ERE SI- ORI MONAMONA SI- ORI OONI SI- AOKO ERAN __ SI -
AOKO EGBO AKEREJUPON SI- #AKIYESI_ ((( IBI TI ABATIWU- AKEREJUPON- AOFI
OBI OLOJU META KAN SI OJU IBE )))
AOJO PELU- ESTATE - META - AOLO EBU NA - AORO SINU ADO ATO - AOPA EJE -
ODO AGUNTAN SI LARA - AOFI ERAN NA SE SAARA
ORI EGUN AJA DIE - ORI EGUN OWAWA DIE - AOLO PAPO - AOFI TE IFA IRU EKUN-
AO DA SINU EFE OWU - AOFI OWU DUDU ATI FUNFUN WE - AOPE OHUN RE SI - AO
WA GBE OKUTA LE MOLE - WALAHI ORI YIO BEERE SINI FO ORI ELEDA TI APE
ORUKO RE SINU GBOLOHUN RE -
GBOLOHUN RE :- BI AJA BA GBO ORI AMA FO AJA - IWO L OMO L NI ORI FO BAYI
O- BI OWAWA BAKE - ORUN RE YIO WOLE - L OMO L IWO NI ORUN RE WOLE BAYI
OOOO - AO WA GBE OKUTA LE IKOBEERE NA LORI
0 0 0 0
0 0
0 0
0 0
AO PE-
#PSALM_RE_
AROLOMI- 3*
AJIFAMOLA- 3*
NDANDABIRI SE ESE MEJEJI YEBEYEBE
AREMO AFIOJU KO OWO OLOWO
ENI ENI TI OBATI MO ORUKO EYIN AGBAGBA MERERIN ILU - ENI OJU OWO KONI
PON OLUWARE MO- OJU IRE GBOGBO KONI PON OLUWARE MO- EMI L OMO L - MO
ORUKO EYIN AGBAGBA MERERIN - EMA JEKI OJU OWO O PON MI - EMAJEKI OJU
IRE GBOGBO PON MI •
AROLOMI- LORUKO TAN PE IWO IFA- NI IJO TI OJU OWO NPON O- ISU KOKO LOJE-
TI O FIDI OLOWO - EMI L OMO L - NA JE ISU KOKO KIN DI OLOWO •
AJIFAMOLA - LORUKO TI ANPE IWO ODU - NI IJO TI ARA NI O- ISU EWURA LOJE
KI ARA FI RO FUN O - PESE EMI L OMO L - NA JE ISU EWURA KI ARA ROMI PESE •
NDANDABIRI SE ESE MEJEJI YEBEYEBE - LORUKO TI ANPE IWO ESU ODARA- AKO
ISU LOJE LOFIDI OLOWO- LOFIDI OLOLA - LOFIDI ONI RE - GBOGBO EMI L OMO L -
NA JE AKO ISU - KIDI OLOWO- KIDI OLOLA- KIDI ONI RE GBOGBO•
AREMO AFIOJU KO OWO OLOWO - LORUKO TI ANPE EYIN IYAMOGUN AJE - EPO
LE MU- LEFIDI OLOWO - LEFIDI OLOLA - LEFIDI ONI RE GBOGBO- EMI L OMO L NA
MU EPO - KIDI OLOWO- KIDI OLOLA •
AO DA IYERE OSUN NA SINU- ASARO NA- TI OBADI ARO OJO KEJI- KATO FOHUN-
AOKO JE
LILO AGBARA AIYE
OKAN ERAN AGU - ATI - ISU GBEGBE - PELU OKAN IJAKUMO- AOKO SINU- PANSA
IGBA - AOLO RIMO ORI ATAN- FUN OJO MEJE - KI OJO MEJE - TOPE ANIKI -
ALABOYUN LOYA - IGBE SORI IKANNTI ABO MOLE YEN- KI OJO MEJE TOPE - TI
OJO MEJE BAPE - AOLO WU - AOLO JO NI OJUGBO- TI ABA TI NJO LOWO- AWON
EYE GUNNUGUN YIO MA FO - WON YIO BA KALE - WON YIO YIRAPADA DI EYAN- TI
WON BATIDE ODO WA - AO MU DIE SINU EBU YEN - AO WA MALO - AWON AGBA YIO
GBE ELE TOKU - TI ABA TI DELE- TOBA DI OJO KEJI- AOFI EBU TI ABU YEN- AOFI
SINGBERE - LATI OKE ORI IDODO WA SI OOKAN AYA WA LOKE -
LILORE:- AOFI OWO TI AFI BU EBU YEN - AOGBELE ORI IGBEERE YEN- AOSI SO
OHUN KOHUN TOBA WUWA - HMMMM OTIDI OSHA TI OBA RI ISE YI SE
#SISERE_ AO LO GBOGBO OMO ESTATE YEN SI IBI- KAN NA - AOLO EFO EBOLO -
OOJO - MO EWE ALURO OOJO- AOFI WON - KO ESTATE TI ALO YEN - DADA - AO KI
ORUKA META SINU RE - AO YI ROBO - AO LA ENU ANKEERE - OOJO AKO- SI ENU RE
- AOFI OWU DUDU- ATI FUNFUN WE DADA- AOLORIMO ORI ATAN - FUN OJO MEJE -
LEHIN AOFI IGI YO - ORUKA AO SA SABE ILE KOGBE -
OROGBO KAN- OBI ABATA OLOJU META KAN- ODIDI ATARE KAN- AOKO SINU APE
- AOKO EWE AMUNIMUYE LE LORI- AOJO TOBA JOTAN- AO LORA AGADAGODO -
ONIGUN MARUN- AO WA DA EBU YEN SINU OWU AKESE - AO WA MU EMU
ALAGBEDE - AOFI EGBE RE LE - AO GBE EBU TOWA NINU OWU AKESE YEN LE -
AO JEKI IDI EMU ALAGBEDE- YEN YO SITA - AO WA FI OWU DUDU ATI FUNFUN WE
DADA
LILORE :- AOTE ASO PUPA KAN SILE - AOFI MU AGADAGODO YEN DANI- AOSOPE -
OSEBELE 3* AOFI ORI AKUKO KAN LEEMETA - AOSOPE ADIE RE RE OOO- KOWA
MU EJE ADIE YI LESEKESE OOO - AO WA GBE AGADAGODO YEN SORI ASO PUPA
YEN- AO WA MU ADIE AKUKO KAN DANI- AOKO ESE RE ATI IYERE SI SEYIN-
AO GBE OKAN AYA ADIE YEN LE - AGADAGODO YEN - AO JE ATARE LENU- AO BU
OTIN SENU- AOJE AO TUN SI AGADAGODO NA NILELE LORI ASO YEN- AO WA GBE
ADIE YEN LE
AO MA SOPE -
OFORE:-
SANGO KI KOHUN - OROGBO - IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O- ORISHA KI
KOHUN OBI- IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O- EMU KI MURI TI LAGBEDE - EMU KI
KOHUN ALAGBEDE- IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O- OWU DUDU ATI FUNFUN
KI JARAWON NIYAN- KI KOHUN ARA WON OOO- IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O -
OSEBELE 3* ADIE RE RE - KOWA MU EJE ADIE YI LESEKESE BAYI BAYI - AOPE
OFORE NA SI - TITI YIO FI KU
AKIYESI:- ABUDO NI- IMULE LARA DAADAA OOO- AMO TABA RI WIPE - KOPA
ADIE NA LESEKESE - WIPE OKAN WEAK RE NI- AJE WIPE IMULE WA KOTO NIYEN-
AO WA PA ADIE NA LE LORI BEEEE- AMO YIO WEAK ADIE NA SA - TAJA WIPE KONI
LE SALO MO- YIO TIMU NINU EJE RE DIE - TIKOBA WA KU - DAJUDAJU KOSI IMULE
LARA WA NIYEN- AO PA ADIE NA SI - AO TUN IYE ABIYA ATI- AYA RE SI LARA - AO
MA TOJU RE SINU ASO PUPA