Você está na página 1de 4

ORIKI OBALUWAYE

ILE MO PE O
OBALUWAYE
OBALUWAYE ODUN RE NI AWA SE
MA JE KI A RI IKU
MA JE KI A RI ARUN
AGAN TI KO RI EJA RE O
MA JE KI A RI IGBONA
JE KI A LEKE
OBALUWAYE A JE IGBA OGUN MA KU
OTA ILE, OTA ODE
OSO ILE ATI AJE ILE
OTA OKUNRIN, OTA OBINRIN
OTA OMODE, OTA AGBA
OBALUWAYE BA WA PA GBOGBO WON RU PATAPATA
FARI ORO, ONI WOWO ADO
ORUMO LOGUN DANU
OBALUWAYE SANU IYAWO
O PA OKO RE TAN
O FI ORI RE JO OGUN
SANU FUN GBOGBO WA O
GBOGBO ENI BA NPE ORI WA NI IBI
OFO LOMI, EFO NSE
OFO NI KI GBOGBO WON O SE KALE AYE WON
ORISA JINGBINI
ABATA, ARU BI EWE AJO
ORISA TI NMU OMO UM IYA,
BI OBALUWAYE BA UM WON TAN,
O TUN LE SARE LO UM BABA,
ORISA BI AJE
OBALUWAYE MO ILE OSO, O MO ILE AJE
O GBA OSO L’OJU,
OSO KUN FINRINFINRIN
O PA AJE KU IKAN SOSO
ORISA JINGBINI
OBALUWAYE A UM NI TOUN TOUN
OBALUWAYE SI ODU RE HAN MI
KI NDI OLOWO
KI NDI OLOMO
OMO EBEDU
EDU ILARA
OMO ALASE OJU OMI
OMO AFEPE WE
OMO AFIJA BA WON DA BUDO
OMO ARORO KO WON LOJU OGUN
ELEGBEE BORISA BOGIBOGI
BABA OKE
BABA KIJIPA ASO TI BEMII DIJE
OMO AGORI ODO JIYAN
A FAYA GBOMO PON KADUN TORI IKU NI
ORUN IRE OO

ADURA OBALUWAYE

AJI BA ERIN DE
A UM ERIN WA LO
ODARA O JADI
OMO A TOYEE
O LO BI BABA MI AROKO
NIJO EBO LE
O F OJU RI SONA ERO
A MU IWA GUN
MA F OJU RIN ILE SODO MI
JE OLU YI O GUN O

ADURA OBALUWAYE

ORISA JINGBINNI
ABATA, ARU BI EWE AJO
ORISA TI NMU OMO MU IYA
BI OBALUWAYE BA MU WON TAN
O TUN LE SARE LO MU BABA
ORISA BI AJE
OBALUWAYE SEBI O MO ILE OSO ATI AJE
OGBA OSO LOJU
OSO KU FINRINFINRIN
O PA AJE KU IKAN SOSO
ORISA JINGBINNI
OBALUWAYE A MU OMO TOHUN TOHUN
ONIBU ORE
ENI TOFOTI LO LAGBAYI
OMO A BURUKU
OLOTO
ELEGBA OMO A DI PELEMO
NIJO OGUN
JAJUN NPON OTI A NJO
ELEMOSO NPON OTI A NYO SESE
OLOYE NLA NI YOO FI OTI RE MU
BABA MI NI A SIN ABIKU RELE IYA RE
IGBA TI O SIN MI RELE IYA MI
NI MO TO DURO
BABA MI JOKO SIBA NILE AWON
ONISE ONA, NITORI KANNI
OWO ALAWO SIBA LORUN JAGUN
AYO KO YENI
A NLE JAGUN NINU ILE
O NMO ILE KUN ILE
ANPE KI JAGUN O MA LO
O NFI ISU ERUPE BALE
A LE JAGUN TITI
APAKO KA JAGUN MO
MIMO ILE NI O NMO ILE KIRI
WUWO NINU OYE A MORI
ONI ILAGBA EFON
MA NA MI KI O MA SE NA OMO MI
KEMBERI IRUN ORI RE NI EGBA AJI
GAMBARI O NDI TIRE NI EGBA KAN
A TONI LOYE GBE
O DIRUN TIRE NI OKE MEJI
OMO AGAN O FEREKI
GBIGBE NI A MAA GBE ALAGEMO
KI O TO WO ILE
FIFA NI A MAA FA OTO NPORO WO OJA
BI E BABA MI GBE JAGUN
KO NI DIDE
JAGUN MA GBE EGBE RU BI OSE
ENI ODIGBA ILEKE YE KO NI ORUN ILEKE
ENI OYE NLA YE KO NI ORUN LAGIDIGBA
JAGUN BA OKO RE
ORU AGAN OMO ERAN KU KI NKI AWO

ADURA OBALUWAYE

ERU MOWO
OLORI OLOOLO
KINIUN ARA IGBO INA-ESA
ERU TI NBA ERU NINU JE
ARUWE KO SE OGUN AGBEDE TOUN PELU EYO
TAPA MAA FI OGO OWO TONU
MAA FI EJI OKO TELE NI MOBA
OGAA ARA KATA KA NI OWO
OGAAA ARA ILU OSINGIN
IDE LO NFE MI NILE BI KO SI ENI
ADIGO JA
OHUN MO BA WA O JU TI ORI ENI LO
OGARA WON KI JE IRU
OGARA WON KI JE OGIRI
KO GBODO JE YANRIN
NITORI YANRIN NI IYA EEGUN
OMO ENI JE OGUMO ATI ODO
BI ONI KOLE NI-WARIN
ASE ABE ROKOSO BI OJO YO
OGA TI NMI MAA MI SOKE BI EKURO
ABIDAYO BABA MI OMO AGBALAJA BI ESAN
OGARA OMO ONILE REFUREFU
OGARA OMO ONILE REFUREFU
NIBI TI A RI EYE TI A KO RI OKO FI PA EYE

OFO - ADURA PARA ASSENTAMENTO DE OBALUWAYE

OBALUWAYE
ERU MO IYI OWO
BABA AWON ALABE
EKUN INU IGBO
ERU TI NPA ERU LEKUN
ATUWE O SE OGUN EYO
TAPA, MA MOWO RA OUN GBOGBO
ONILE OWO
OLONA OLA
ONILE IYI
MO GBE E JOKO BABA
MO NI O KI NJE IRU
BENI O KI NJE OGIRI
GBUGBURU NI OUN BABA
GUDUGUDU NI ILU RE
BABA A JI JE PETEKI TOUN ODO
BI A BA WURE
WA GBO IWURE WA
OBALUWAYE TENREN BI EKURO
OBA NINU IGBO,
NIBI TI A RI ERAN
TI A KO RI OUN FI PA
OBALUWAYE IBA
SOPONA IBA
ENYIN ELEYE TI E NI AYE
TOUN ILE, IBA
OSANYIN, KI O JE EWE, O JE
OSANYIN, KI O JE ORISA, O JE O

Você também pode gostar