Escolar Documentos
Profissional Documentos
Cultura Documentos
* * * * * *
* * * * ** **
* * * * * *
* ** * * * **
Oworin Sogbe Inverso do Odu Osé Bireté
* ** * * * *
* ** * * * **
* * * * ** *
* * * * * **
Obara Ogbe Iwori Ofun
* * ** **
* ** <opicional se caber> * *
* ** ** *
* ** * **
Faça o consulente tocarem as oferendas na cabeça e no peito e que faça suas orações
pessoais.
O Babalawo pega algumas penas (ou pelos) da nuca, do peito e da cabeça (quando
possível) e coloca no eko do ebo.
Coloque búzios em cima do dinheiro e peça que o cliente toque com a cabeça e no peito e
faça as orações e pedidos pessoais. Depois disso o cliente deve coloca o dinheiro com os
búzios no centro do opon.
Após isso o Babalawo deve recitar IBA
Iba Baba
Iba yeye
Iba Oluwo
Iba Ojugbona
Iba atiwaye ojo
Iba atiwo oorun
Iba Eegun Idile mi
Olodumare Iba re
Olojo oni Iba re
Eyin Iyami Osoronga Iba yin
Iba Esu odara
Iba tototo, mo juba o!
Orunmila nle
IFA olookun asoro dayo eleri ipin
ajeju oogun bolajoko omo eere lapa
okinkin timu eyin erin fon
odundun tidun ori ile mere
kori ilemere moba sefo oloja oseduo ninu ebora
kogbeni ti kolani ti.
(Mao direita) Otun awo aba lodifa funwon lode aba ifa toda fun won lode aba se
(mão esquerda) Osi awo abose ifa toda funwon lode abose se
(mão direita)Ati owo otun
(mão esquerda em cima) ati owo osi won kiigbe ebo funni aimoda
Yoyo ni tile oyo wa apa nitile alapa bo
Wuruwuru nrode owu
Difa funwon lode asewele
Asewele modem oni depenu
Aba degun depe lawo lri koleja
Egun o PA elegun epe o PA elepê sawere Pepe sare wa PA elepê funmi
sawere Pepe
Depois tocando com o dinheiro e os búzios no cliente
Consulente
Omo
(cabeça) kepe Omã baja ki orire BA Ru ebo na
(peito)ki ayare bada ebo naa ki ayare mo wo opon olopon emeta lakeepe fun oloja
Èsù-perewe, Egba-perewe.
A dífá f’Olú Oge
ti o koro l’eje t’omot’omo,
a d’ewé Jogbó,
aya Oge koro.
Àkùko meta,
egbetala owó
àti ewé Jogbó (ewuro) tiise ewé Ifá.
Bi eniti a dà Ifá yi fún ba rúbo
kiofi omi gbo ewé ewuro
kioko iye-iròsù Ifá yi da sii,
kio gbee mu.
Ifá fihan’ni pe aya eni naa ti a dífá yi fún nja
tàbí ayé dojuko O.
Òtóótó
Òróóró
Òtòòtò làá jèpà
Òtòòtò làá jèmumu
Lótò lótó ni wóón folú esunsuun sénu
Ohun torí ni torí
Ohun tòòri ni tòòri
Ohun torí tòòri làá rò fÒba Mòkín ní òde Ìrànjé
Kí Onirànjé ó lè baà fòtòtò èèyàn tani lórẹ
Béèrún bá jà tó bá tà
Wón a fòwó lówòó
Wón a fi giyàn balè
A dífá fún Ògo tééré
Èyi ti ń gbóguún lợ ilú gbèňdù gbẹndu èyin ợwợnràn
Wón ni kí Ògo tééré ó rúbợ
Ògo tééré si gbó ẹbợ
Ó rú
Ò gbo eeru
Ifa kojekebo naa ofin koje ki ebo naa oda
Koje ki ebo naa de ode orun koroko jako
Won ní oná wò lo gba tóòfi nje bè
Mo ní bee náá lóò je ifa
OYEKÚ MÉJÌ
Oye sese nlabo loke
Wonse bi mimo ni ojumo nmo
Adifa fun eja tise Omo onibu
Kosi ibi ti agbe kan odo
Takan Omo eja
Omo eja
Mo ti papoju.
Ifa kojekebo naa ofin koje ki ebo naa oda
Koje ki ebo naa de ode orun koroko jako
Won ní oná wò lo gba tóòfi nje bè
Mo ní bee náá lóò je ifa
IWORIIMEJI
ODI MEJI
Odindi Odi
Odindi Odi
Eji Odi meji, a di otito
D'ifa fun Akesan, ti o nlo ree je Baale oja
Akesan nd'ade, aya re nda oja
Eyin o mo pe olori ire ni eni nd'aja
Ifa kojekebo naa ofin koje ki ebo naa oda
Koje ki ebo naa de ode orun koroko jako
Won ní oná wò lo gba tóòfi nje bè
Mo ní bee náá lóò je ifa
Ifa kojekebo naa ofin koje ki ebo naa oda
Koje ki ebo naa de ode orun koroko jako
IKA MEJI
Etusesefi’nu-igbose’le,
Oniwakawakafi’nu-isase’budo
Won dífá fún Bara Àgbonnìrègún
nlos’ode Ife lo se ire omobibi
Okà méjì àti abo adìye méjì ni ebo
Ó gbo ó rú.
O gbin okà, okà gbo tan, o se méjì
Nínú re, O fi bo Olusupen re.
Won ni: Eyiti o se okà méjì ti ofi
bo Olusupen re, Kiamaapee ni Ìkáméjì
Eniti a dá Ifá yi fún yoo bimo
púpo tàbí oun yoo re púpo nínú ayé.
Ifá I o di Alájubaraka,
Emi I o di Alájubaraka.
Bi aba lo Jubaraka ki o Jubaraka,
Obi Olotooro,
O bi Oloteere.
O bi Onàwofunmirin.
Onàwofunmirin liobi Ajé,
Ajé liobi Ènìyàn.
Ajé di o r’ okun,
Ènìyàn di ore Irada.
Ose! kiosaregege re i mu Ajé wa fun mi nilé Olókun ...
Ìrete! kiosaregege re Irada kiolomu Ènìyàn fun mi wa. ...
Ape! kiomajeki Ire mi pe kiotoo de.
Ejirin! kiomajeki Ire mi, rin jinna kiotoode.
Biagba’le-gba’na odo atitan li aiko ori re si.
Abe de awo kira lokifa fun kira nijo tin fi ojoojumo sowo aseti
Abede loni awo kira edumare maje nse aseti laye.
O babalawo entrega o búzio para o cliente que deve tocar na cabeça e no peito e fazer as
orações pessoais e depois deve colocar “enterrado” no eko.
Se não for:
Depois pergunta para OPELE se vai Azeite de Dendê (EPO)
Depois pergunta para OPELE se é suficiente
Se não for:
Depois pergunta para OPELE se vai Sal (IYO)
Depois pergunta para OPELE se é suficiente
Se não for:
Depois pergunta para OPELE se vai Cinzas(ERU)
Depois pergunta para OPELE se é suficiente
Se não for:
Depois pergunta para OPELE se vai Mel (OYIN)
Depois pergunta para OPELE se é suficiente
Se não for:
Depois pergunta para OPELE se vai Gin (OTI)
Depois pergunta para OPELE se é suficiente
Se todas perguntas forem negativas pergunta- se a OPELE se todos os itens vão no Ebo.
Omi
Epo
Gùrugùru gùègùè
Díá fún EpoTííí se omo ìyá Ebo
Epo gorí i rè ó d`Ebo
Gùrugùru gùègùè
Epo gorí i rè ó d`Ebo
Gùrugù gùègùè
Iyo
Ayoyo GO ayoyo GO
Ayoyo gomogomo
Adifafun orunmila baba nlore bawon um iyo yora
Awa tabawon um iyo yora oro ayo niko mobawa
Oro ibanuje kan kiiba iyo
Oyin
Okanran funfun ninini
A difa fun Oyin
Igba tit orun bo wáyè
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nbe o rubo
Ruru ebo ruru atekesù
E wà ba ni jebutu rere
Nje a kii la oyin ka roju
Oro oyin kó si dun
Oti
Òtúrá lalèmu
Ìretè lalèrà
Díá fún Àrànìsàn
Tí yóó muti kan àmulòwò
Oti olà lawo ń um
Depois pergunta para OPELE se o Ebó vai ser entregue a ESU (frente )
Se não for:
Pergunta para OPELE se o Ebó vai ser entregue a OROCO (esquerda)
Se não for:
Pergunta para OPELE se o Ebó vai ser entregue a IDI AKUKO (árvore de akuko)
Se não for:
Odu da Consulta
* *
* *
* *
* *
Inverso do odu
* *
* *
* *
* *
IWORIIMEJI
** **
* *
* *
** **
ODI MEJI
* *
** **
** **
* *
IKA MEJI
** **
* *
** **
** **
IRETE MEJI
* *
* *
** **
* *
IWORI OFUN
** **
* *
** *
* **
OSÉ IRETÉ
* *
* **
** *
* **
OSA OTURA
* **
** *
* *
* *
Depois entrega o Ebo ao cliente que deve baforar 3 x e fazer as orações pessoais.
Depois apoia-se a oferenda no opon e faz a reza com o irukere em mãos
Depois o cliente deverá entregar o ebo no lugar determinado, voltar e tocar a cabeça no
chão para ifá e com as mãos apoiadas no opon e viradas para cima o babalawo apoia o
irukere nas mão do cliente e reza Osa Di
Osa Di
Adimulaerin okun
Adimulaerin Osa
Erin dikinmuerinyaso
E fondimu efon yajana
Agbamureredimuohuiwo kán sososlori girogiro
Manjagbani
Manjagbarare
A D’Ifa fun Alááka
Ti odi opoopemunitoríabiye Omo
Opemodiomukiomayinminu
Iyirè ara igi kííwannu
Ijoarun BA nbò koobo
Ijo gbogbo ajogun BA nbò koobo
Ijoaje bà nbò kóò síí silé
Iyo Ire gbogbo BA nbò kóò síí sílé