Escolar Documentos
Profissional Documentos
Cultura Documentos
Awọn ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá Ànaàgó fún alákọbẹ̀rè Julho de 2019 revisão 170719 IGHB PDF
Awọn ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá Ànaàgó fún alákọbẹ̀rè Julho de 2019 revisão 170719 IGHB PDF
Awọn ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá Ànaàgó fún alákọbẹ̀rè Julho de 2019 revisão 170719 IGHB PDF
Olukọ́ Adelson
2019
1
Awọn ẹ̀ kọ́ èdè Yorùbá-Ànàgó fún alákọbẹ̀ rè, Apa kìíní / Lições
de língua Iorubá-Nagô para iniciantes Primeira Parte
Índice
–Ẹ kàárọ̀ o! / Ẹ kàásán o –
Se àlàáfiíà ni?
Ara ile n kọ́?
Iṣẹ́ n kọ́?
Orúkọ mi ni Olukọ́ Adelson de Brito.
Emi ni olukọ́ yin.
Emi ni yóò kọ́ yin ni èdè Yorùbá.
Mo ní ìrèti pé óò gbadun àsikò yi.
Edè Yorùbá dùn púpọ̀ lati kọ́.
Bótilẹ̀jẹ́pé ó ṣòro díẹ̀ lati mọ̀.
Ṣe o ti gbọ́?
Tradução
-Bom dia! /Boa tarde!
Como vai, tudo bem?
E a família?
Com vai o trabalho?
Meu nome é Adelson de Brito.
Eu sou seu professor
Eu vou te ensinar na língua Iorubá.
Eu espero que você aproveite bem este ciclo.
A língua Yorùbá é doce de aprender.
Embora seja um pouco (trabalhosa) dificil.
Você entendeu?
1
Ifé é uma antiga cidade iorubá no estado de ọṣun Osun, no sudoeste da Nigéria. Evidências
arqueológicas indicam que o início da povoação da cidade remonta a 500 a.C.
1.2. ABD Alífábẹ́ ẹ̀ tì Yorùbá/O ABD Alfabeto Iorubá Yorùbá/ O Alfabeto
Iorubá
Alífábé è tì
Alifabẹẹtì ni àkójòpò awọn lẹta ti a fi n kọ èdè silẹ. Lẹta marunlelogun (25)
ni alifabẹẹti yorùbá máa n ni. Àwọn lẹta yorùbá ni:
A B D E Ẹ F G Gb H I J K L M N O Ọ P R S S̩ T U W Y
a B D e ẹ f g gb h I j K l M N O o Ọ ọ p r S s̩ t u W Y
B D F G Gb H J K L M N P R S S̩ T U W Y
b D F g gb h j K l M N p r S s̩ t uw y
OBSERVAÇÃO:
Ọ é pronunciado como o “o” das palavras: olhar, norte, forte, camarote, etc.:
Jẹ ki a sọ àwọn lẹta ti o wa ni Alífábé ẹ̀ tì Yorùbá, nipa lilo àwọn ọ̀ rọ̀ ti o
lorukọ lojoojumọ nkan
Tradução:
Vamos pronunciar as letras do alfabeto Iorubá, usando palavras que nominam objetos
do cotidiano:
http://www.coerll.utexas.edu/yemi/
Veja também esse treino de pronúncias das letras do alfabeto, no link abaixo
https://www.youtube.com/watch?v=FBdmAKDRECg
C c, Q q, V v, X x, Z z
Ṣùgbó n Yorùbá ní
Ẹ ẹ, Ọ ọ, Ṣ ṣ
1.4. Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá/ O tom é o pilar da língua Iorubá Iorubá
Àkíyèsí: A kì í sábà fi àmì si orí ò rò olóhùn àárín àfi lé è kò ò kan nígbà tí ó bá
yẹ.
Nota: De um modo geral, não se coloca acento sbre as sílbas com tonalidade
média, a não ser nos casos em que isso se faça necessário.
1.5. Ètò ọ̀ rọ̀ ni a ń pè ni Mọfọ́ lọ́ jì/Estrurua das palavras ou Morfologia
O ṣe pàtàkì lati ní ìmò tí ó péye nípa ètò gígé ẹyọ ò rò sí è bù- è bù ni èdè
Yorùbá nítorí pé ẹyọ kò ò kan ni ó ní ìró ohùn tirè
Àpẹẹrẹ/Exemplos
A ti dé – Nós chegamos
Ẹ ti dé – Você chegou
Ó ti dé – Ele/Ela chegou
Kó ńńsonáǹtì ati Fáwè li àpapọ gé gé bíi sílébù kan
Àpẹẹrẹ/Exemplos
Má lù mi – Não me bata
Mò ǹ lọ – Eu estou indo
Àpẹẹrẹ/Exemplos
Rédíò (mí-mí-dò)
Òòyà (dò-dò-dò)
Ọkọ̣̀ (re-dò)
Kẹ̣̀kẹ̣́ (dò-mí)
Ọmọlan̄ke (re-re-ree-re)
Ìwé (dò-ré)
Ẹfun (re-re)
Rúlà (mí-dò)
Pátákó (mí-mí-mí)
Bọ̣́ọ̣̀lù (mí-dò-dò)
Òdòdó (dò-dò-mí)
Olúṣẹgun: Báwo ni o?
Tolúlọ̣́pẹ́: Dáadáa ni.
Olúṣẹgun: Ó mà tọjọ mẹ́ta
Tolúlọ̣́pẹ́: Bẹẹ ni o ọjọ kan pẹ̀lú
Olúṣẹgun: Ṣé àlàáfíà ni?
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Àlàáfíà ni.
Olúṣẹgun: Iṣẹ́ ńkọ́?
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Ó ń lọ dáadá.
Olúṣẹgun: Gbogbo ilé ńkọ́?
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Wó n wà.
Olúṣẹgun: Àwọn bàbá àti mama ńkọ́?
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Wó n wà.
Olúṣẹgun: Àwọn ẹ́gbọ́n rẹ ńkọ́?
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Wọn wà, a dúpẹ́
Olúṣẹgun: Bá mi kí bàbá àti màmá rẹ.
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Wó n wà gbọ́.
Olúṣẹgun: Ó dàbọ̀ o.
Tolúlọ̣́pẹ̣́: Ó dàbọ̀.
Tradução do diálogo I
Iorubá Português
Báwo ni o? Como vai?
Dáadáa ni. Muito bem
Ó mà tọjọ mẹ́ta. Faz tempo (há quanto tempo, etc.:)
Bẹẹ ni o ọjọ kan pẹ̀lú Sim,(verdade) faz tempo.
Şé àlàáfíà ni? Você está em paz? (Você está bem?)
Àlàáfíà. Paz, bem estar, etc.:
Àlàáfíà ni. Vou bem.
Iṣẹ́ n kọ́? O (seu) trabalho vai bem?
Ó n lọ dáadáa. Ele (o trabalho) vai bem.
Gbogbo ilé n kọ́? Todos em casa (a familia) vão bem?
Wọn wà. Todos bem.
Àwọn bàbá àti mama n kọ́? Seus pais (pai e mãe) vão bem?
Wọn wà. Todos bem.
http://www.africa.uga.edu/Yoruba/unit_01/lesson1.html
Odó Pilão
Rédiò Rádio
Òòyà Pente
Ọkọ̀ Enxada
Kẹ̀kẹ́ Bicicleta
Ọmọlaṅke2 Carrinho
Ìwé Livro
Ẹfun Giz
Rúlà Régua
Pátákó Prancha de madeira
Bọ́ọ̀lù Bola
Òdòdó Flor
Ilé Casa
Ibusun Cama
Tabili Mesa
Obinrin Mulher
Ọkúnrin Homem
Ọmọdebinrin Menina
Ọmọdekunrin Rapaz
Bàbá Pai
Íyá Mãe
Ẹgbọn ọkunrin Irmão mais velho
Aburo ọkunrin Irmão mais novo
Ágbàdo Milho
Eré Brincadeira
Ò gbé ni Senhor
Iyaafin Senhora
Ìrẹsì Arroz
Ọmọ Filho, filha, criança
2
É um carrinho feito de madeira usado nas feiras para transportar compras.
GB gb àti P p
1.10. Àwọn ọ̀ rọ̀ ti o tọka si eniyan ibi tabi nkan (àwọn ọrọ) / Palavras
relacionadas a gente, ou coisas (substantivos) ]
Ile [Casa] Ọrẹ [Amigo]
2. Ìkíni tabi kiki ni je̟ àşà pàtaki ninu àwọn Yorùbá / A saudação ou
cumprimento é uma tradição importante para os Iorubá
Ìkíni
Nigbati ọmọ kekere ba fẹ́ ki agbalagba, kibaṣe ọkunrin, kibaṣe obinrin, “ẹ” ni yió
wi. Nitorina, nwọ̀n lati bowó fun awọ̀n ti o ba jú nwọ̀n lọ.Yió sọ pe “Ę kàárọ̀” tabi
“Ę kabọ̀”. Ǫkunrin ndọ̀bálẹ̀, obinrin, o si nkunlẹ lati ki ení t´o ba jú nwọ̀n lọ.T´o ba
sepe ọkọ rẹ ni, o le pe “Ę kàárọ̀ o, ọkọ mi”. Eyi jẹ́ àṣà ti wòpọ̀ laarin Yorùbá. Àwọ̀n
agbalagba má sọ pe ọmọ kekere ko gbodo yaju si agbalagba.
Tradução
Saudações
Quando as crianças pequenas (jovens), saudam os adultos, seja para saudar homem,
seja para saudar mulher , devem usar o prefixo "Ẹ." É assim que eles mostram respeito
pelas pessoas mais velhas que eles encontram. Eles devem dizer "bom dia" ou "você é
bem-vindo". Os meninos devem se prostrar no chão, as meninas devem se ajoelhar
para saudar as pessoas mas velhas que eles veem. Se for no caso esposo, a esposa
deve dizer "Bom dia, meu marido". Esta é uma prática comum entre os Iorubá. Os mais
velhos costumam ensinar (dizer) que as crianças não devem ser rude com adultos.
Ẹ káàbọ
Um cumprimento que voce usa para dizer “Bem-vindo” a uma pessoa que
chega em sua casa e é mais velho do que você.
Caso seja você a pessoa que retorna e é recebido por uma pessoa, mais
velha, que lhe diz:
Káàbọ O
Wó n é outro pronome regular usado para sinalizar respeito em Iorubá. Por
exemplo, quando lhe perguntam como está sua mãe ou seu pai, você
responde "wó n wà" (ele / ela está indo bem), mesmo que wó n seja um
pronome do sujeito plural da terceira pessoa.
Tradução
Saudando os mais velhos
Por favor, observe que ‘Bawo ni', em Iorubá, é para cumprimentar a todos. As
crianças e jovens utilizam para cumprimentar uns aos outros. Mas não se usa para
cumprimentar os mais velhos. É uma forma ofensiva ou desrespeitosa do jovem
para com o mais velho. A forma de cumprimentar os mais velhos,é dizer, por
exemplo ...
Bom dia-
Boa tarde-
Boa noite -
Mò ń lọ
Estou indo
Enquanto que
Èmí lọ
Eu fui
Mo lọ
Eu fui
Ìkíni Ìdáhùn
Ní àárọ̀
Ę kú àárọ̀ o. òo
A ò jí bí o? A dúpẹ́ o
Alàáfíà kọ́ bí? A dúpẹ́ o
Ara ò le bí? A dúpẹ́ o
Ní ọ̀sán
Ę kú àsán o. òo
Ní ìròlẹ́
Ę kú ìròlẹ́ o. òo
Ę kú àsáálẹ́ o. òo
Ní alẹ́
Ę kú alẹ́ o. òo.
Vai ser um eufemismo dizer que as saudações são práticas queridas dos
Iorubás. Pode-se dizer também que as saudações são inseparáveis do Iorubá,
porque esta é a primeira coisa que um estrangeiro nota quando conhece o povo
Iorubá. Na verdade, os homens e mulheres Iorubás resgatados da escravidão
pelos navios de guerra britânicos que se estabeleceram em Freetown na atual
República da Serra Leoa no início do século 19 eram conhecidos e chamados
de "Aku" (como já foi referido acima), que é uma corrupção do prefixo “ Ę kú” que
Vamos traduzir!
Yorùbá Português
Orúkọ àmútọ̀runwá mi ni
Ìdòwú. Meu nome natural3 é Idowu.
3
O nome natural dado a uma criança yorùbá, é aquele que revela as circusntâncias que marcam o seu
nascimento. Assim, nesse exemplo, o nome “Idowu” simboliza o nascimento dessa criança após o
nascimento de gêmeos. O nome “Idowu” é unissex.
Tradução
Tradução
Yorùbá Português
levante a mão!
(singular, informal)
ṣe ó yé ẹ ? você entende ?
http://www.coerll.utexas.edu/yemi/
– Ẹ káàbò o, Màmá
– Àlàáfíà ni.
– Wó n wà nílé.
– Ó dáa. Dide
– Ẹ káàrò mà
– Dáadáa ni mà
– Bé è ni mà
2.8.4. Ṣadé ń ki ọ̀ rẹ́ rẹ, Funmi, ni ilé-ìwé ni ọ̀ sán/ Sade cumprimenta sua
amiga, Funmi, na escola pela tarde
– Káàsán o, Fúnmi
– Káàsán o, Ṣadé
– A dúpé
2.9. Ẹ jẹ ki a gbé èdè àti àṣà Yorùbá Lárugẹ! / Vamos manter a viva a
Língua Iorubá!
Orúkọ mi ni Wálé. Mo jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn láti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè
Nàìjíríà. Tí ó bá di ọjọ́ kẹsàn-án, oṣù kọkànlá ọdún tí ó ń bọ̀ ni màá pé ọmọ
ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n.
Tradução
“Lati ọjọ́ ti aláyé ti dá ayé ni Yorùbá ti ni ìgbàgbọ́ ninu ki a gba àdúrà nitori
pe ohun gbogbo fẹ́ àdúrà “Ohun ti o dára fẹ́ àdúrà ki ó bà lé dára si, eyi ti kò
dára na fẹ́ àdúrà ki ó bà lé yanjú”. Bi àwọn “Ìgbàgbọ́ tàbi ilé-àdúrà aláṣọ
funfun” ti ńlo “Àbẹ́là...”
Tradução
Desde o prinicipio do mundo que o povo iorubá sempre acreditou em orar
porque todas as coisas requerem oração. "O que é bom exige oração para seu
sustento, o que é ruim exige oração para sua solução". Como os "católicos
usam "Velas" para rezar ...
Iṣẹ́ ṣiṣe
Pésè Ìdáhùn sí awọn ọ̀ rọ̀ wọ̀ nyí/Forneça as saudações compatíveis com
as respostas seguintes:
1. _______________________________________? Wó n wà
2. _______________________________________? A dúpé
4. _______________________________________? Wó n wà
5. _______________________________________? Dáadáa ni mà
6. Dárúkọ awọ̀n ilú/orilẹ̀-èdè mẹ́wa ti orúkọ wọn bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú lẹta ´B´
7. Orilẹ̀-èdè melo ni Àfríkà ati Amẹ́rikà ni orúkọ wọn bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú lẹta ´N´?
8. Dárúkọ awọ̀n ilú/orilẹ̀-èdè mẹ́wa ti orúkọ wọn bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú lẹta ´B´
_______________________________________________________
...
9. Wo awòrán (máàpù) ilẹ̀ Káàrọ̀-oò-jíire ti ó wa ní ayee loke kí o sì dárúkọ̀
awọ̀n ìlú yorùbá ti ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú lẹta ´O´ ati ´I´.
___________________________________________________
Abala kìíní.
Gbogbo ènìyàn ni a bí ní òmìnira; iyì àti è̟tó̟ kò̟ò̟kan sì dó̟gba. Wó̟n ní è̟bùn ti
làákàyè àti ti è̟rí-o̟kàn, ó sì ye̟ kí wo̟n ó máa hùwà sí ara wo̟n gé̟gé̟ bí o̟mo̟
ìyá.
Tradução
Artigo primeiro
O tọjọ́ mẹ́ta!
Kini tuntun?
Ṣé dáadáa le wa?
Ṣé dáadáa le dé?
Com propõe o “The Yoruba blog”: Ẹ jẹ ki a gbé èdè àti àṣà Yorùbá Lárugẹ:
Vamos manter a viva a Língua Iorubá
Bem-vindo à 3ª aula sobre de Língua e Cultura Iorubá-Nagô.
Há quanto tempo!
Quais as novidades?
Yorùbá Português
Mo Eu
O tú, você
Ó ele, ela
A Nós
? vocês
wọn eles,elas
Yorùbá Português
Èmi Eu
Ìwọ Você
Àwa Nós
È yin Vocês
Olúṣẹgun: Báwo ni o?
Tolúlọ̣́pẹ́: Dáadáa ni.
Yorùbá Português
mi Meu
wa nosso, nossa
“Ńkọ́” é uma palavra especial aqui que significa mais ou menos, “...também
está/estão bem? ”
. Em geral, eles são usados para vincular umas palavras as outras, como por
exemplo: eu falo Iorubá e Inglês a preposição é [e] porque conecta ambas as
palavras Yoruba e Inglês. Segue uma lista das preposições mais utilizadas em
Iorubá:
Yorùbá Português
ati E
loke Acima
nisalè Sob
ṣááju Antes
lẹhin Depois
jina si longe de
nítòsí perto de
inu Dentro
laisi Sem
nipa sobre, a respeito de
ṣugbó n Porém
fun Para
lati Desde
Yorùbá Português
4
ju ... lọ é a forma de expressar “do que” em Iorubá.
Yorùbá Português
Báwo Olá!
Ẹ káàrọ Bom dia
Ẹ k´asan Boa tarde
Ẹ k´alẹ Boa noite
Báwo ni, Orẹ mi Como vai, meu amigo
Bawo lowa Como vai (tipo: E aí?)
Bawo lara Como vai? (polido)
Mo wà dada, Ẹ ṣe Eu vou bem, obrigado
Ìwọ́ na ńkọ́? E você? (informal)
Ìwọ́ ńkọ́? E você? (polido)
O da Bem
Kòfibẹ Não muito bem
O tọjọ́ mẹ́ta 5 Há quanto tempo (não te vejo)
Ọjọ́ kan pẹlu 6 Sim, realmente
Kini tuntun? Que há de novo
Ko si tuntun Sem novidades
Ẹ ṣe gan Obrigado
Adupẹ Obrigado
Ko t´opẹ Por nada
Inu mi dún Prazer
Wole wà Entre! (Pode entrar)
Ìdágbére/despedidas
5
“O tọjọ́ mẹ́ta”, significa literalmente “fazem três dias”
6 “Ọjọ́ kan pẹlu” significa literalmente “um dia a mais”.
7 “Od´ārọ́” significa até a manhã, onde “ārọ́” é a contração de “Owurọ”, ou seja, “raiar do dia”,
“amanhecer”, etc
Ẹgbọn rè ọkunrin ńkó ? /Aburo rè Daadaa ni wó n wà/ Alaafia ni wó n wà
ọkunrin ńkó ? /
(Como vai seu irmão mais velho/seu (Vai bem. Obrigado/a)
irmão mais novo)
Vejam o vídeo:
https://www.youtube.com/watch?v=FgYYbmIi5kY (acessado em
13/05/19)
Oşù keji ọdún ní orílẹ̀-èdè Amẹ́rika (USA) jẹ́ àsìkò ti wọn máa şe ìrántí ìtàn
àwọn adúláwọ̀ ti o jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́rika. Nínú oşù yii, ni àwọn ará ilẹ̀
Amẹ́rika máa bojúwo ẹ̀hìn láti ránti onírúrú ohun ti o şẹlẹ̀ si ènìàn aláwọ̀-dúdú
sáà kan. Işe riribi ti Martin Luther King àtí àwọn àşiwajú òmìrán, şe lati jà fún
ẹ̀tọ́ (àti ìgbélarugẹ ipò) àwọn adúláwọ̀ ni ilẹ̀ Amẹ́rika pẹ̀lú ọ̀nà lati pèsè
idogbándógba nípa:
– ẹ̀tọ́ fún adúláwọ̀ lati dibò ;
– àyípadà àwọn òfin ti o ya ọmọ aláwọ̀-dúdú sọ́tọ̀ ni ìlé-ìwé,
– ẹyawó láti ra ile,
– àti àwọn ètò ìrànlọ́wọ́ míràn, jẹ́ nkan ìwri nlá fún gbogbo èniyàn aláwọ̀-dúdú
káàkiri àgbáyé.
source
Tradução (04/03/17)
______________________________
___________________________________
_______________________________________________
___________________________________
________________________________________
___________________________________
Íbèrè Idahun
Ki ni orúkọ rẹ?
Ibo ni ò ngbé?
3. Lo arọ́ pò orúkọ ìní 8tó tọ́ nà/ Use o pronome possesivo correto
Bí àpẹẹrẹ/Por exemplo
Bàbáa Túndé = Bàbáa rè
1. Bàbá àti mámáa Títí
______________________________
2. È gbó nọn Jídé
______________________________
3. Àbúròo Títí àti Wálé
____________________________
4. Àbúròo bàbáa Wálé
_____________________________
5. Màmá èmi àti ìwọ
_______________________
6. Ìwé ìwó
____________________________
7. Pé ńsùlù è yin
_________________________
8. Kíláàsì àwa àti è yin
____________________
8
aró pò orúkọ ìní = pronome possesivo
Pesquise e responda
Ni igbà àtijọ̀, ó jé ohun pataki yálà fun ọkunrin tabi fun obinrin lati ṣe Ìgbéyàwó.
Ni igba ti a gbadura fun eniyan ni ilẹ̀ Yorùbá pé yóò ṣe anfaani ṣíṣe ti bèrè ni ibi
Ìgbéyàwó.
Tradução
Ni ẹ̀kọ yìí, a máa kọ nípa àwọn ọrọ ti a sábàá ń ló fùn Isò rò ngbèsì gbogbogbò
ni èdè yorùbá.
Tradução:
Nesta lição, aprenderemos sobre as palavras mais comuns nos diálogos em língua
Iorubá.
Jẹ ki a kọ bi a ṣe le ṣe òdi. Fun apere: Wipe ‘kò si’ tabi ‘Emi kò le ṣe, Emi kò
a.b.b.l.9
Tradução
Vamos aprender a negação. Por exemplo: dizer 'não' ou 'eu não posso, eu não faço
etc.
Yorùbá Português
9
a.b.b.l. é a abreviatura de ati bẹẹ bẹẹ bẹẹ lọ que significa ‘ e assim por diante’, ou mesmo ‘etc.’.
Yorùbá Português
Bẹẹ ni Sim
Rara Não
Kò yé mi Não entendo
Ó yé mi Eu entendo
Ẹ ṣé Obrigado
Mo fẹ ẹ Eu gosto disto
Ìjọba-àpapọ̀ sọ Èkó di ìpínlẹ̀ ni àádọ́ta ọdún sẹhin. Èkó jẹ́ olú ilú fún gbogbo
orilẹ̀ èdè Nigeria tẹ́lẹ̀ ki wọn tó gbe lọ si Abuja. Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ ikan ninú ipinle
mẹ́fà Yorùbá.
Yorùbá ni “Èkó gba olè, ó gba ọlẹ”, ọ̀rọ̀ yi jẹ wi pé kò si irú ẹni ti ko si ni ìpínlẹ̀
Èkó nitori Èkó gba olówó, ó si gba aláini àti wi pé iṣẹ́ pọ̀ ni Èkó ju gbogbo ìpínlẹ̀
yoku lo. Kò si ẹ̀yà tàbi ẹ̀sìn Nigeria ti kò si ni Èkó. Nitori èyi èrò pọ̀ jù ilẹ̀ lọ
nitori omi ló yi Èkó ká.
Tradução
O governo federal da Nigéria criou o Estado de Lagos cinquenta anos atrás. Lagos era
a capital da Nigéria antes de ser (a capital) transferida para Abuja. Lagos é um dos seis
estados iorubás.
Segundo um provérbio iorubá “Lagos acomoda tanto os ladrões quanto os preguiçosos”,
ou seja, ricos ou pobres, qualquer pessoa pode morar em Lagos, pois não há nenhum
grupo étnico ou relgião que não esteja representado/a no Estado por conta de ser este
estado rodeado por cursos d´água.
Iṣẹ̣́ ṣíṣe
3. Báwo ni máa ṣe sọ “Eu não sei” ni èdè yorùbá. Kọ Ìdáhùn rẹ silẹ
ní ààyè tó wà ni isalẹ.
(B) Ò yé mi
(C) Kú ori-ìre
(D) Ẹ ṣe
5. Jẹ ki àwọn itakurọsọ wọnyi wà bí o ṣe yẹ
( ) Ẹ ṣe A) Não
( ) Ẹ kú abọ C) Obrigado
Gégé bí àwọn oyìnbó Gèé sì sẹ ni òrìṣà ti wó n ti jin ọjó kọọkan ni aàrin ò sè
ni àwọn Yorùbá náà ni òrìṣà ti wọn n bọ nínú àwọn ọjó tó wà láàrin ò sè .
Báyìí àwọn òrìṣà ti Yorùbá fi jin ọjọ kọọkan ni à ó sọ.
Tradução
Da mesma forma que os europeus fazem com respeito aos santos que cultuam
em cada dia da semana, os Iorubá também cultuam (ligam) os dias da semana a
cada santo. Assim, os santos que os Iorubá cultuam em correspondencia com os
dias da semana são assim distribuidos.
Orúkọ Gẹ̀é sì Orúkọ Yorùbà Itàn tó rọ̀ mó ọjó kọọkan
Tradução
Erele / Fevereiro
Erena / Março
Oduduwa:
O nome Oduduwa é a compilação ou compressão dos termos da frase
(“odudu ni ewa” ou seja o pigmento escuro é a beleza; oddu= o pigmento
escuro; ni ewa= é a beleza) / Iyaagbe (IYA, mãe; Agbe, que recebe) = Orixá
da Terra e matrona da Ayé. Oduduwa dota o pigmento da cor do ébano da
pele escura, o qual concede maiores dons de espiritualidade, beleza e
inteligência ao portador. A essência do amor procriador. Oduduwa é
festejado em Erena / 15 - 19 (Março). Oshosi = Orisa da Aventura e da caça
é homenageado no mes Erena / 21 Março - 24:
Ibge / Abril
Mes dedicado ao Orixá Ogun, o Orisa do metal e ofícios de guerra e de
engenharia. O guardião da verdade e executor da justiça, como tal, patrono
das profissões jurídicas e aconselhamento que deve jurar defender a
verdade, enquanto morder um pedaço de metal.
Oxum = Orixá da fertilidade e guardião da essência feminina. Orixá que
orienta a gravidez a termo.
Èbìbí / Maio
Okudu / Junho
Ogun / Agosto
Òwéré / Setembro
Ọwara / Outubro
Oya (Orixá do “odo Oya” = rio Níger, cujo mensageiro é Afefe (o vento), e
guardião do portal entre o mundo físico (Aye) e do reino espiritual (Òrún).
Ọwaro Osun (Orisa do odo Osun = Rio Oxún) e patrono (soberano) da
nação Ijebu nação: Ọwaro terceira semana de outubro
O início da estação seca (outono)
É dedicado a Shigidi, o Orixá de Orun-Apadi, o reino dos espíritos
pendentes e dos fantasmas dos mortos que deixaram Aye e são impedidos
de acessar ao Orun-Rere. Depositários dos pesadelos e padroeiros dos
assassinos.
Belu / Novembro
Ope / Dezembro
A le máa wá lórí Google Search láti rí púpọ̀ nípa àṣà Yorùbá bí i èdè,
àwòrán, àpóti-amóhùn-máwòrán, ìròyìn àti oríṣiríṣi ìtan Yorùbá. A tún ní
Google Search tí ó nlo èdè Yorùbá, a sì ní Wikipedia fún Yorùbá,
nairaland.com àti yorupedia.com. Ọ̀nà dáradára wọ́nyìí ni láti bá ara ẹni
sọ̀rọ̀ nípa ìṣe Yorùbá, a sì fi gbogbo náà hàn sí àwọn láayé. Láìpẹ́ ẹ̀rọ
ayélujára máa ṣe ju láti yára wá rí ìṣé Áfíríkà fún ilẹ̀ Náíjíríà.
Tradução
Podemos pesquisar no Google Search para saber mais sobre a cultura Iorùbá, coisas
como a língua, programas televisivos, blogs, boletins informativos e várias histórias
iorubás. Também podemos pesquisar no Google Search diretamente no idioma Iorubá
diretamente no site nairaland.com e na yorupedia.com. Essas são formas que permitem
manter o diálogo entre os interessados sobre as práticas iorubás, e mostramos a elas
todas elas. Mais cedo ou mais tarde, os radiodifusores eletrônicos farão mais do que
encontrar rapidamente empregos e oportunidades de trabalho na Nigéria.
Yorùbá Português
tabi
Ko si nkan kan.
http://www.africa.uga.edu/Yoruba/unit_03/index.html (acessado em
02/01/3)
Adéwálé: O ti, ẹbí mi kò tóbi rárá, Mo ní bàbá, ìyá àti àbúrò mẹ́ta.
Orúkọ àwọn òbí mi ni Olóyè Adéògún àti Arábìnrin Títílayọ̀. Orúkọ àwọn
àbúrò mi ni Tádé, Tóyìn àti Tólú. Tade jẹ ọkùnrin ṣùgbọ́n obìnrin ni Toyin
ati Tolu. Gbogbo wọn n gbé ní ìlú Òndó pẹ̀lú àwọn òbí mi.
Şé o ri wí pé ẹbí mi kéré. Jẹ k’a lọ kí àwọn òbí mi.
Olúṣẹgun: Kò burú (Wọn jade)
Iorubá Português
Kí nì yẹn? O que é isto?
Àwòrán bàbá àti ìyá mi nì É o retrato dos meus pais
bàbá àti ìyá Papai e mamãe
Níbo ni wọn n gbé? Onde (eles) moram?
Wọn n gbé ní Òndó Eles moram em Ondo
Şe ẹbí rẹ tóbi? Sua família é grande?
O ti, ẹbí mi kò tóbi rárá, Não, minha família não é grande
Mo ní bàbá, ìyá àti àbúrò mẹ́ta Tenho pai, mãe, e três irmãos
menores.
Orúkọ àwọn òbí mi ni Os nomes dos meus pais são
Olóyè Adéògún àti Arábìnrin Títílayọ̀ Chefe Adeogun e Dona Titilayo
Orúkọ àwọn àbúrò mi ni Tádé, Tóyìn Os (nomes dos meus) irmãos são,
àti Tólú. Tade,Toyin, e Tolu.
Tade jẹ ọkùnrin ṣùgbọ́n obìnrin ni Tade é homem, porém, Toyin e Tolu
Toyin ati Tolu. são mulheres.
Gbogbo wọn n gbé ní ìlú Òndó pẹ̀lú Todos moram (estão morando) na
àwọn òbí mi . cidade de Ondo com meus pais.
Şé o ri wí pé ẹbí mi kéré. Você vê que minha família é
pequena.
Jẹ k’a lọ kí àwọn òbí mi. Vamos cumprimentar meus pais.
*Kò burú *Fique tranquilo (Expressão usada
aqui com o sentido de “sim, vamos”).
f. Ębí Adéwálé kò
□ sanra
□ kéré
□ tóbi
IMPORTANTE: (Àwòran bàbá àti ìyiá mi ni) Para a próxima aula voce
vai trazer um retrato de família (não precisa ser a sua) e explicar sobre
os membros aqui na classe.
Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti
pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma
nri àwọn òbí mi. Lati ọjọ́ Ajé titi dé ọjọ́ Ẹti, mi o ki ri ìyá àti bàbá mi nitori
súnkẹrẹ-fàkẹrẹ ọkọ̀ ni Èkó, wọn yio ti jade ni ilé ni kùtùkùtù òwúrọ̀ ki n tó ji,
wọn yio pẹ́ wọlé lẹhin ti mo bá ti sùn.
Tradução
A sexta-feira é quinto dia letivo da semana. Eu fico feliz porque as aulas terminam
à 1:00 da tarde e começa a folga (semanal). Eu amo os finais de semana porque
encontro meus pais. De segunda a sexta não vejo minha mãe nem meu pai. Eles
saem muito cedo pela manhã, quando ainda estou dormindo (para evitar os
engarrafamentos das ruas de Lagos), eles voltam para casa muito tarde eles
chegavam logo depois que eu estava dourando eu já estou dormindo.
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2018/07/What-I-love-about-the-
weekend-break.wav (acessado em November 23/12/2018)
1. Oókan
2. Eéjì
3. Ęẹ́ta
4. Ẹẹ́rin
5. Aárùn-ún
6. Ẹẹ́fà
7. Eéje
8. Ẹẹ́jọ
9. Ẹẹ́sàn
10. Ẹẹ́wàá
11 16
12 17
13 18
14 19
15 20
5.2. Dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀ nyí ní ẹ̀ kúnrẹ́ rẹ́ / Responda as
seguintes questões usando formas completas.
________________________________________________________
________________________________________________________
3. Kí ni bàbáà ń tà? (aṣọ)
________________________________________________________
4. Kí ni ìwọ ń ṣé ? (kàwé)
________________________________________________________
5. Kí ni wó n ń ṣé ? (jé un)
________________________________________________________
6. Kí ni a fé jẹ? (oúnjẹ)
________________________________________________________
7. Kí ni wó n ń kọ ? (ìwé)
________________________________________________________
8. Kí ni è yin ń tà? (irẹsi)
________________________________________________________
9. Kí ni Olú ń fé ? (owó)
________________________________________________________
10. Kí ni awa ati è yin ni? (àlàáfià)
________________________________________________________
Ọdún Kérésì jẹ́ ọdún Onigbàgbọ́ lati ṣe iránti ọjọ́ ibi Jésù Olùgbàlà. Ọjọ́ kẹjọ
lẹhin ọdún Kérésìmesì ni ọdún tuntun. Fún ayẹyẹ ọdún, kò si iyàtọ̀ laarin
Ìgbàgbọ́ àti Mùsùlùmi ni ilẹ̀ Yorùbá nitori Yorùbá gbà wi pé “Ẹni ọdún bá láyé, ó
yẹ kó dúpẹ́”. Ọpẹ́ ló yẹ ki èniyàn dá ju igbèsè ji jẹ lati ṣe àṣe hàn ni àsikò ọdún.
Ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹhin, àwọn Àgbẹ̀ á dari wálé pẹ̀lú irè oko pàtàki iṣu. Àwọn
Oniṣòwò á ri ọjà tà nitori àsikò yi ni Bàbá àti Ìyá ma nrán aṣọ ọdún fún àwọn
ọmọdé àti oúnjẹ rẹpẹtẹ fún ipalẹ̀mọ́ ọdún. Inú ọmọdé ma ndùn nitori asiko yi ni
wọn nse irẹsi àti pa adiẹ fún ọdún. Àwọn ọmọdé á lọ lati ilé ẹbi kan si ekeji, ẹbi
ti wọn lọ ki, á fún wọn ni oúnjẹ àti owó ọdún. Àwọn àgbàlagbà naa ma ndá aṣọ
ẹgbẹ́ fún idúpẹ́ ọdún, ṣùgbọ́n ki owó epo rọ̀bi tó gba igboro, ki ṣe aṣọ olówó nla
bi ti ayé òde òni.
Àsikò ti olè npọ̀ si niyi pàtàki ni ilú Èkó, nitori ọ̀pọ̀lọpọ̀ fẹ na owó ti wọn kò ni lati
ṣe ọdún. Ìpolówó ọjà pọ̀ ni àsikò yi ni Òkè-Òkun, nitori eyi, ọ̀pọ̀ nlo ike-igbèsè
tàbi ki wọn ya owó-èlè lati ra ọjà ti wọn kò ni owó rẹ. Lẹhin ọdún, wọn a fi ọdún
tuntun bẹ̀rẹ̀ si san igbèsè, nitori eyi Ìyá àti Bàbá a ma a ti ibi iṣẹ́ kan lọ si ekeji
lai ni ìsimi tàbi ri àyè àti bójú tó àwọn ọmọ.
Ọ̀rọ̀ Yorùbá sọ wi pé “Ṣe bi o ti mọ ki i tẹ́ ”, nitori eyi gbogbo ọmọ Yorùbá ni ilé,
ni oko, ẹ ṣe bi ẹ ti mọ, ẹ ma tori odun na ọwọ́ si nkan ti ọwọ́ yin kò tó, ki ẹ ma ba
a tẹ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Onigbàgbọ́ ayé òde oni ki i fẹ fi èdè Yorùbá kọrin ṣùgbọ́n ẹ gbọ́
bi ọmọ Òyinbó ti kọ orin àwọn “Obinrin Rere” ni ojú iwé yi.
Novo. Como resultado, ambos os pais devem trabalhar sem descanso ou sem tempo
para cuidar dos filhos.
De acordo com um ditado iorubá, “Aquele que age moderadamente não será
desonrado”. Isso deve ser aplicável aos iorubás, tanto no pais natal, quanto no exterior,
para busquem fazer as coisas com moderação e não gastar o dinheiro que não podem
pagar para não passar desonra, depois das festas de final de ano. Hoje em dia, muitos
cristãos não cantam usando a língua iorubá, mas assista abaixo como uma jovem
branca canta com alegria a música “Good Women Choir's”.
Opin/Fim
Referências:
Opin