Escolar Documentos
Profissional Documentos
Cultura Documentos
oturopon ofun:
OBI
_________________obi ni iyi o
obi ni nbe iku
obi ni nbe arun
obi ni nbe ejo
oun naa ni nbe ota
a ba e be gbogbo ohun buruku ile aye
TRADUÇÃO
Òròrò ma rò
A díá fún Obì
Obì tí n sawoó ròde Gbànja
Ajé ni n ò ní ni mo wáá rò fún o
Òròrò ma rò
Awo lobì
Awo ni gbànja
Aya ni n ò ní ni mo wáá rò fún o
Òròrò ma rò
Awo lobì
Awo ni gbànja
Omo ni n ò rí bi mo wáá rò fún o
Òròrò ma rò
Awo lobì
Awo ni gbànja
Tradução
Ororo ma ro
Fez divinação para o Obì
No dia em que ia viajar para divinar na casa de Gbanja
Minha carência de riqueza é pelo que venho reclamar
Ororo ma ro
O Obì é um Awo
Gbanja também é Awo
Minha falta de esposa é pelo que venho a oferta-lo
Ororo ma ro
O Obì é um Awo
Gbanja também é Awo
Eu não tenho filhos é o que venho contar-te
Ororo ma ro
O Obì é um Awo
Gbanja também é Awo.