Escolar Documentos
Profissional Documentos
Cultura Documentos
006 Lição 6
006 Lição 6
(1)
Àbúrò wa ṣe ẹbọ fún Èṣù. Bàbá rẹ̀ jẹ́jẹ̀ ẹ́ gèlè kan fún Ṣadé.
(2)
Mo fún ọmọ mi ní ìwé kan. N kò fún Adé ní owó.
O fún ẹ̀ gbọ́n mi ní bàtà yẹn. O kò fún mi ní àwọn obì náà.
Obìnrin náà fún wa ní fèrè kan. Ọkùnrin náà fún mi ní orógbó díẹ̀ .
Ṣé o fún ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀ bùn náà? Bẹ́ẹ̀ni, mo fún ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀ bùn náà.
Ṣé o fún bàbá wa ní aṣọ yìí? Rárá, mi ò fún bàbá wa ní aṣọ yìí.
Ṣé ìyá rẹ̀ fún ọmọdé náà ní èso? Bẹ́ẹ̀ni, ìyá rẹ̀ fún ọmọdé náà ní èso.
Ṣé o fún Ṣadé ní igbá náà? Rárá, n kò fún Ṣadé ní igbá náà.
(3)
Àṣìṣe kìíní:
Х ____________________________________
О ____________________________________
Àṣìṣe kejì:
Х ____________________________________
О ____________________________________
Àṣìṣe kẹta:
Х ____________________________________
О ____________________________________
_____________ o
_____________ o
_____________ ______ ______ ____________ gbé jó
Exercício 1 Traduza as sentenças abaixo para o português:
1) Ọ̀ rẹ́ mi fún ọmọdé yẹn ní orógbó púpọ̀ .
2) O kò fún mi ní ìwé yìí.
3) Ṣé bàbá rẹ̀ fún wa ní àwọn aṣọ pupa?
4) Ọ̀ rẹ́ Kẹ́mi fún obìnrin yìí ní àpò kan.